Jump to content

Anamero Sunday Dekeri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Anamero Sunday Dekeri
a suited man standing between two flags
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kẹ̀wá 1969 (1969-10-25) (ọmọ ọdún 54)
Ogute-Oke, Okpella
Ẹ̀kọ́Ambrose Alli University, Ekpoma
Iṣẹ́Member House of Representative Etsako Federal Constituency
Political partyAll Progressives Congress
Websiteanamero.com

Anamero Sunday Dekeri jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Nàìjíríà, òun ni aṣojú àgbègbè Etsako lọ́wọ́ lọ́wọ́ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣojú Nàìjíríà.

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Anamero Sunday Dekeri sí abúlé Ogute-Oke, Okpella, Ìpínlẹ̀ Edo, Nàìjíríà. Àwọn òbí rẹ̀ ń sin ẹranko. Dekeri gba ìwé-ẹ̀rí rẹ̀ àkọ́kọ́ láti ilé ìwé Ugbedudu Primary School àti ìwé ẹ̀rí Ṣekọ́ndírì láti ilé ìwé Ogute-Oke Secondary. Ó tún gba ìwé-ẹ̀rí Bachelor of LawYunifásítì Ambrose Alli, Ekpoma. Ó kàwé gboyè náà ní Nigeria Police College, Ikeja.[citation needed]

Dekeri bẹ̀rẹ̀ òsèlú ní ọdún 2019, a sì yàn án gẹ́gẹ́ bi aṣojú ìwọ Etsako ní Ilé ìgbìmọ̀ aṣojú Nàìjíríà lábé ẹgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress (APC) party. Ó mú àdá dídá of Federal Medical Center kalẹ̀ ní Uluoke, Edo State,[1][2] àti ìdá Federal College of Technical Education, Okpella Ìpínlẹ̀ Edo.[1]

Ní ọdún 2023, Dekeri fi ète rẹ̀ láti du ipò gómìnà fún gómìnà Ìpínlẹ̀ Edo hàn,[3][4] lábé ẹgbẹ́ òṣèlú APC. Àwọn ìpolongo rẹ̀ dá lórí ète rẹ̀ láti mú ìyípadà ọ̀tun bá ẹ̀kọ́, ìlera ara, isẹ́ àgbè, oúnjẹ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "BILLS DEPARTMENT HOUSE OF REPRESENTATIVES 10TH NATIONAL ASSEMBLY" (PDF). nass.gov.ng. Retrieved 2024-01-16. 
  2. "Bills". Anamero (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-01-16. 
  3. TVCN (2023-12-04). "Anamero Dakari Declares For Edo Governorship Under APC - Trending News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-01-16. 
  4. Hon Anamero Dekeri's Declaration Speech for Edo Governorship 2024 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), retrieved 2024-01-16 
  5. "Hon Anamero Dekeri Declaration Speech for Edo Governorship" (PDF). anamero. 2023-12-04. Retrieved 2024-01-16.