Arárọ̀míre
Ìrísí
The Figurine: Araromire | |
---|---|
Adarí | Kunle Afolayan |
Olùgbékalẹ̀ | Golden Effects |
Òǹkọ̀wé | Kemi Adesoye[1] |
Asọ̀tàn | Lagbaja |
Àwọn òṣèré | Ramsey Nouah Omoni Oboli Kunle Afolayan Funlola Aofiyebi-Raimi Tosin Sido |
Orin | Wale Waves |
Ìyàwòrán sinimá | Yinka Edward |
Olóòtú |
|
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Golden Effects Studios Jungle FilmWorks |
Olùpín | Golden Effects Pictures |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 122 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè |
|
Ìnáwó | ₦50[2]- 70 million[3] |
Owó àrígbàwọlé | ₦30,000,000 (domestic gross) [4] |
The Figurine: Arárọ̀míre jẹ́ eré amóhùn máwòrán tí ójáde ní ọdún 2009 tí Kemi Adesoye kọ, tí Kunle Afolayan ṣàgbéjáde àti atọ́kùn, rẹ̀ tí ó sì tún kópa nínu rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìkan gbọ̀n. Ramsey Nouah àti Omoni Oboli kópa nínú rẹ̀.
Eré yìí sọ ìtàn àwọn ọ̀ré méjì tí wọ́n rí ère alágbára ní ojúbọ tí wọ́n ti pa tì nínú igbó nígbà tí wọ́n ń ṣàgùnbánirọ̀, tí ìkan nínú wọn gbé ère yìí lọlé. Láìmọ̀ pé ère Arárọ̀míre tí ó maa ń gbé ire fún ènìyàn tí ó bá ri fún ọdún meje pẹlú ìyà ọdún méje míràn tí ó tẹ̀le. Ayé àwọn ọ̀ré méjì yìí bẹ̀ẹ̀rẹ̀ sí ní dára, tí wọ́n sì ń ní ìlọsíwájú àti ìgbéga nínú iṣẹ́ àti okùn òwò wọn. Síbẹ̀síbẹ̀, lẹ́yìn ọdú méje yìí, Gbogbo nkan bẹ̀ẹ̀rẹ̀ sí ní dàrú fún wọn.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Kunle Afolayan - Review of The Figurine". Lagos, Nigeria: The Punch Online. Retrieved 13 April 2010.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Vourlias, Christopher (5 June 2010). "Nigerian helmer leads 'New Nollywood'". Variety (New York, USA: Reed Business Information). https://www.variety.com/article/VR1118020218.html?categoryid=1019&cs=1.
- ↑ "The Figurine raises the bar of Nigerian filmmaking". Lagos, Nigeria: Naija rules. Archived from the original on 3 December 2013. Retrieved 30 September 2009.
- ↑ "'Half Of A Yellow Sun' Confirmed As Nollywood's Most Expensive Movie". Lagos, Nigeria: Naij. http://news.naij.com/31426.html.
- ↑ Folch, Christine.
- ↑ Idowu, Ayo (23 April 2010). "A review of Kunle Afolayan’s award-winning movie, Figurine". Nigerian Tribune (Ibadan, Nigeria). Archived from the original on 6 May 2010. https://web.archive.org/web/20100506025225/http://www.tribune.com.ng/index.php/weekend-starter/4445-a-review-of-kunle-afolayans-award-winning-movie-figurine. Retrieved 10 March 2011.