Aulliminden

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
Aulliminden
Regions with significant populations
 Niger
Nàìjíríà Nàìjíríà
Èdè

èdè Tawallammat

Awon Aulliminden jẹ́ ọ̀kan nínú ẹ̀yà Tuareg. A lè rí wọn ní orílẹ̀-èdè Niger àti ní apá àríwá Nàìjíríà.