Mumuye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

MUMUYE[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn wọ̀nyí jẹ ara ènìyàn Naijiria, wọn kere niye, wọn si da dúró tẹlẹ ni. Ipinle Taraba ni wọn n gbe ni Jalingo. Wọn le lẹ́gbẹ̀rún lọ́nà irínwó. Isẹ́ Lagalagana ni wọn ń ṣe.