Ìran Isoko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ọmọ Isoko)
Aworan ijo awon soko

Ìran Isoko jẹ́ è̀dè Edoid, ọ̀kan lára àwọn èdè tí a lè rí ní ìpínlẹ̀ Delta. Lápa gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ni apá Niger Delta. A tún lè rí àwọn tí wọ́n ń sọọ ní ìpínlẹ̀ Bayelsa.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]