Ìdomà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Idoma)
Omobìnrin Idoma tí ó wo aso àwò aláràbarà ti Idoma tí ó sì nsun isu.

Èdè Idoma A lè rí Ìdomà ní ààrin gùngùn orílẹ̀ èdè Náígíríà. Àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ igba méjì ati àádọ́ta ẹgbẹ̀rún. Àwọn aládùgbóò rẹ̀ ni Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Idoma ni wọ́n jẹ agbẹ. Wọ́n si máa ń se àpọ́nlé àwọn baba ńlá wọn tí wọ́n ti kú.