Ìdomà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Èdè Idoma A lè rí Ìdomà ní ààrin gùngùn orílè èdè Náígíríà. Àwon tí wón ń so èdè yìí jé igba méjì ati àádóta egbèrún. Àwon aládùgbóò rè ni Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Òpòlopò àwon Idoma ni wón je agbe. Wón si máa ń se àpónlé àwon baba ńlá won tí wón ti kú.