Jump to content

Aurelian

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aurelian

Aurelian jẹ́ ỌbalúayéIlẹ̀ Ọbalúayé Róòmù. Àpèjá orúkọ rẹ̀ ni Lucius Domiticus Aurelianus. Ìwọ̀n ọjọ́ ayé rẹ̀ ni c 215-270, ìyàwó rẹ̀ ni Ulpia Severina, ọmọ re ni Waliballat, Vaballathus ni ede latin. O je ọbalúayé lẹ́yìn Quintillus. Ẹni àkọ́kọ́ tí ó ṣégun Alemanni àti Juthungi. Wọ́n kọ́ ògiri sí ilẹ̀ Róòmù ní orúkọ rẹ̀ ní 271. Wọ́n ṣe owó sílẹ̀ ní orúkọ rẹ̀ (coin of Aurellian).