Jump to content

Nero

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nero

Nero je obaluaye ni Ile Obaluaye Romu. Nero (/ˈnɪəroʊ/ NEER-oh; oruko ni kikun: Nero Claudius Caesar Augustus Germanicus; ọjọ karunla oṣù Kejìlá ni AD 37 sí ojo kesan osu keje ni AD 68) je ọba karun ati oba to kẹyìn ni ìjọba ti Julio-Claudian, o si jọba lati AD 58 titi ti ofi seku párá ẹ ni AD 68. Ni igba ti owa ni omo odun metala ni ọba Romu Kìlọdiọ̀sì ti gba gẹgẹ bíi omo rẹ ti osi je aremo oba naa. Nero je eniyan olókìkí lọdọ awọn èsọ̀ rẹ àti awon eniyan to wọpọ ni ilu, sugbon awon lobaloba korira rẹ. Pupo ninu itan ti a kọ nipa Nero so wipe ọ jẹ eniyan búburú ati onisekuse. Leyin ti ọ di oya ilu Romu, o para ẹ ni ìgbà tí o pe ogbon odun.