Didius Julianus

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Didius Julianus
20th Emperor of the Roman Empire
Orí-ìtẹ́ 28 March – 1 June 193
Orúkọ Marcus Didius Severus Julianus
(from birth to accession);
Caesar Marcus Didius Severus Julianus Augustus (as emperor)
Aṣájú Pertinax
Arọ́pọ̀ Septimius Severus
Consort to Manlia Scantilla
Ọmọ Didia Clara
Ẹbíajọba None
Bàbá Quintus Petronius Didius Severus
Ìyá Aemilia Clara

Didius Julianus (Látìnì: Marcus Didius Severus Julianus Augustus;[1] 30 January 133 tabi 2 February 137 – 1 June 193), je Obaluaye Romu fun osu meta ni odun 193. O gun ori ite leyin ti o ti fowo ra latowo awon Eso Praetoria, leyin ti awon wonyi ti sekupa asaju re Pertinax. Eyi lo fa Ogun Abele Romu 193–197 wa. Julianus je lile kuro lori ite, o si bo sowo iku latowo aropo re, Septimius Severus.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. In Classical Latin, Julianus' name would be inscribed as MARCVS DIDIVS IVLIANVS AVGVSTVS.