Jump to content

Awujale

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Awùjalẹ̀̀ ni orúkọ oyè Ọba ìbílẹ̀ Ìjẹ̀bú. Ẹni tó bá wà ní ipò yìí ni wọ́n ń pè ní Awùjalẹ̀ ti Ìjẹ̀bú.[1] Awùjalẹ̀ tó wà lórí oyè lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ọba Sikiru Kayode Adetona Ògbágbá Kejì, tí ó wá láti ìdílé Anikinaiya.

Nínú ìwé òfin ti àwọn lọ́balọ́ba tó ń ṣàkóso ìlú Ìjẹ̀bú, àwọn ìdílé Ọlọ́ba mẹ́rin ni ó wà:[2]

  1. Ìdílé Gbelegbuwa
  2. Ìdílé Anikinaiya
  3. Ìdílé Fusengbuwa
  4. Ìdílé Moyegeso

Ọjọ́ kìíní oṣù kẹsàn-án ọdún 1959 ni wọ́n fi èyí lélẹ̀.

Àtòjọ àwọn Awujale tó ti jẹ sẹ́yìn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • OBA OLU-IWA
  • OBA OSHIN
  • OBANTA – 1430
  • OBA GURU – 1445
  • OBA MUNIGBUWA – 1455
  • OBANTA II – 1460
  • OBA LOJA – 1470
  • OBA LOFIN – 1482
  • OBA APASA – 1496
  • OBA GANJU – 1508
  • OBA TEWOGBOYE – 1516
  • OBA RUWAMUDA – 1520
  • OBA OFINRAN – 1532
  • OBA LAPENGBUA – 1537
  • OBA OTUTUBIOSUN – 1537
  • OBA MOKO IDOWA AJUWAKALE – 1540
  • OBA ADISA – 1552
  • OBA JEWO – 1561
  • OBA ELEWU ILEKE – 1576
  • OBA OLUMISODAN ELEWU ILEKE – 1590
  • OBA MASE – 1620
  • OBA OLOTUSESO – 1625
  • OBA MOLA – 1635
  • OBA AJANA – 1642
  • OBA ORE OR GADEGUN – 1644 (The first female Awujale)
  • OBA GUNWAJA – 1655
  • OBA JADIARA OR OLOWOJOYEMEJI – 1660
  • OBA SAPOKUN – 1675
  • OBA FALOKUN – 1687
  • OBA MEKUN – 1692
  • OBA GBODOGI – 1702
  • OBA OJIGI AMOYEGESO – 1710
  • OBA LIYEWE AROJOFAYE – 1730
  • OBA MOYEGE OLOPE – 1730
  • OBA OJORA – 1735
  • OBA FESOJOYE – 1745
  • OBA ORE JEJE – 1749 (Female)
  • OBA SAPENNUWA RUBA KOYE – 1750 (Female)
  • OBA ORODUDU JOYE – 1755
  • OBA TEWOGBUWA I – 1758
  • OBA GBELEGBUWA I – 1760
  • OBA FUSENGBUWA – 1790
  • OBA SETEJOYE – 1820
  • OBA ANIKILAYA FIGBAJOYE AGBOOGUNSA – 1821
  • OBA AFIDIPOTEMOLE ADEMUYEWO – 1850
  • OBA ATUNWASE ADESINBO – 1886
  • OBA OGBAGBA AGBOTEWOLE I – 1895
  • OBA FUSIGBOYE ADEONA – 1906
  • OBA FESOGBADE ADEMOLU – 1916 (Dethroned)
  • OBA ADEKOYA ELERUJA – 1916
  • OBA ADEMOLU FESOGBADE – 1917 (Enthroned again)
  • OBA ADENUGA AFOLAGBADE – 1925
  • OBA OGUNNAIKE FIBIWOJA – 1929
  • OBA DANIEL ADESANYA GBELEGBUWA II – 1933-1959
  • OBA Dr. SIKIRU OLUWAKAYODE ADETONA, OGBAGBA AGBOTEWOLE II – 1960–present

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ijebu History". ijebumn.org. Archived from the original on 27 January 2017. Retrieved 30 June 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Ijebu Community Association | History". Archived from the original on 13 March 2016. Retrieved 26 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)