Jump to content

Awuke

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
"Awuke"
Fáìlì:Awuke Davido & YG Marley.jpg
Single by Davido and YG Marley
from the album 5ive
Released31 October 2024
Recorded2024
Genre
Length2:53
LabelColumbia
Songwriter(s)
Producer(s)
  • MikabaBeatz
  • Marvey Muzique
Davido singles chronology
"Right Now"
(2024)
"Awuke"
(2024)
"Funds"
(2024)
Àdàkọ:Extra chronology Àdàkọ:External music video

"Awuke" jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orin olórin ilè Nàìjíríà kan, ìyẹn Davido, àti olórin ilẹ̀ America kan, ìyẹn YG Marley. Ó jáde ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù Kẹwàá ọdún 2024, láti ọwọ́ Columbia Records.[1] Davido àti Moonlight AfriQA lọ́ kọ orin náà sílẹ̀.[2] Orin náà wọ àtẹ orin mẹ́wàá tó dára jù ní àtẹ US Billboard Afrobeats Songs.

Lẹ́yìn tí Davido farahàn nínú orin méjì kan, ìyẹn , "Joy" láti ọwọ́ Angélique Kidjo,[3] àti "Right Now" láti ọwọ́ Darkoo pẹ̀lú Rvssian,[4] Davido pinnu láti kọ orin yìí. Ó kọ́kọ́ ṣe ìkéde orin yìí ní ọjọ́ kìíní oṣù Kẹwàá ọdún 2024, lásìkò tí à ń ṣe àjọyọ ìgbòmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,[5] àti níbi ayẹyẹ and Lauryn HillParis, France.[6] Ní ọjọ kejìlélógún oṣù Kẹwàá ọdún 2024, ó ṣe ìkéde lórí ìkànni ayélujára ti X àti Instagram pé orin náà máa jáde ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù Kẹwàá ọdún 2024.[7]

Orin náà jẹ́ àhunpọ̀ Afrobeats àti Amapiano,[8] pẹ̀lú àwọn ohun aládùn pẹ̀lú àwọn ohun èlò orin lóríṣiríṣi.[9][10] Orin náà dá lórí ìfẹ́, pèlú Davido àti YG Marley tó ń kọ nípa ẹwà, àti ìpara-ẹni-mọ́.[11]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Davido Drops His First Single of the Year, "Awuke"". OkayAfrica. Retrieved October 31, 2024. 
  2. Moonlight AfriQA. "Much love bro♥️. Blessed to be a part of OBO's amazing project. #Awuke" – via Twitter. 
  3. Abel (August 28, 2024). "Davido and Angelique Kidjo unite for 'Joy'". TRT Africa. Retrieved October 31, 2024. 
  4. Adeayo Adebiyi (October 11, 2024). "Davido combines with Darkoo for exciting new single 'Right Now'". Pulse Nigeria. Retrieved November 1, 2024. 
  5. "Davido Teases Fans With Snippet of First Single of 2024, Details Emerge". Legit.ng. October 1, 2024. Retrieved November 5, 2024. 
  6. Deborah Bodunde (October 20, 2024). "Davido performs unreleased song featuring YG Marley at Lauryn Hill's Paris concert". TheCable. Retrieved November 5, 2024. 
  7. Musa Adekunle (October 23, 2024). ""Davido announces new single, 'Awuke', featuring YG Marley". The Guardian. Retrieved November 5, 2024. 
  8. "Davido taps Amapiano with YG Marley in 'Awuke'". Syndication. November 4, 2024. Retrieved November 5, 2024. 
  9. "Davido drops new hit "Awuke"". P.M. News. October 31, 2024. Retrieved November 5, 2024. 
  10. "Davido And YG Marley Bring Two Cultures Together On "Awuke"". Style Rave. November 1, 2024. Retrieved November 5, 2024. 
  11. Peter Okhide (October 31, 2024). "Davido and YG Marley unite for new single 'Awuke'". NotJustOk. Retrieved November 5, 2024.