Ayodele Olajide Falase
Ayodele Olajide Falase (ọjọ́ìbí oṣù kẹrìn ọdún 1944) jẹ́ onímọ̀ nípa ọkàn àti ọmọ ilẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ìgbàkeji olórí ilé-ìwé gíga Yunifasiti tí Ibadan. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ WHO lórí àrùn ọkàn-àyà àti lórí ìgbìmọ̀ ògbógi WHO kan lórí àrùn ẹ̀jẹ̀ ọkàn[1].
Ayodele Olajide Falase | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kínní 1944 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Ẹ̀kọ́ |
|
Iṣẹ́ | Dókítà Politician |
Ìgbésí ayé ìbẹ́erẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Ayodele ní ọjọ́ 4 oṣù kìíní ní ọdún 1944 ní abúlé Ẹrin-Oke, Oriade ìjọba ìbílẹ̀ Ìpínlẹ̀ Osun ní orílè-èdè Nàìjíríà.
Ayodele pari ètò-ẹkọ rẹ̀ ní àwọn ilé-ìwé wọ̀nyí:[1]
- Ẹ̀kọ́ gírámà ní Remo Secondary School, Segamu, Lagos State, Nigeria - 1956
- Igbobi College, Yaba - 1957-62
- Yunifásítì tìlú Ibadan - 1963-68
- Royal College of Physicians, UK - 1971
- National Postgraduate Medical College of Nigeria - 1976
- Royal College of Physicians of London - 1982
ìṣe-ṣíṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ayodele bẹ̀rẹ̀ ìsẹ rẹ ní yunifasiti ilé-ìwòsàn kọlẹji, Ibadan ní ọdún 1968-69, léṣekéṣe ti ó jáde ní yunifasiti kán náà. Ó di dókíta ilé ní 1969-70 áti Alákóso ní 1971-72, ni ilé-ìwòsàn kọlẹji kànnà. Ó dì ọpọlọpọ àwọn ipò mú lórí ipá ọnà iṣẹ́ yìí títí ó fì dìde láti dí ọjọ́gbọ́n tí Ẹkọ́ nípa ọkàn àti olúdásílẹ̀ Pan African Society of Cardiology (PASCAR).[2] À fún ún ní Áàmí-ẹri Orílè-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2005 àti lọwọlọwọ ọkàn nínú àwọn Ọjọ́gbọ́n Emeritus mẹ́rin ní Ẹká tí Óògun, Yunifasiti[3][4] Ifáara sí Ayẹwó Ìwòsàn ní Tropics, ìwé akọwé ilé-ìwòsàn tí ó gbajúmọ́ láàárín àwọn ọmọ ilé-ìwé ìṣóogún n ilé-ìwòsàn Nàìjíríà ní akọkọ ṣé atẹjáde nípasẹ̀ rẹ̀ ní ọdún 1986.[5]
Ìwádìí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn atẹjáde Ayodele pẹ̀lú àwọn kókó-ọrọ lóri:
- Arun ọkan ti o wa laelae[9]
- Àkóràn àti àrùn cardiomyopathy [10]
- Awọn arun ọkan ti o bimọ[20]
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Admin (2017-01-25). "FALASE, Prof. Ayodele Olajide". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-08.
- ↑ "I became a professor against my wish". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-01-03. Retrieved 2019-06-08.
- ↑ "Nigerian National Merit Award". www.meritaward.ng. Retrieved 2021-02-10.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Clinical – UCH IBADAN". Archived from the original on 2023-11-09. Retrieved 2023-11-09.
- ↑ "An Introduction to Clinical Diagnosis in the Tropics (January 1, 2000 edition) | Open Library".
- ↑ Falase AO. Endomyocardial fibrosis in Africa. Postgraduate Medical Journal. 1983 Mar 1;59(689):170-8.
- ↑ Falase AO, Ogah OS. Cardiomyopathies and myocardial disorders in Africa: present status and the way forward. Cardiovascular journal of Africa. 2012 Nov;23(10):552.
- ↑ Falase AO, Kolawole TM, Lagundoye SB. Endomyocardial fibrosis. Problems in differential diagnosis. Heart. 1976 Apr 1;38(4):369-74.
- ↑ "Ayodele Olajide Falaise's research works | University College Hospital Ibadan, Ibadan and other places". ResearchGate (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-08.
- ↑ Falase, Ayodele Olajide (1985-03-01). "Infections and dilated cardiomyopathy in Nigeria" (in en). Heart and Vessels 1 (1): 40–44. doi:10.1007/BF02072358. ISSN 1615-2573. PMID 3038833.
- ↑ Ogah OS, Okpechi I, Chukwuonye II, Akinyemi JO, Onwubere BJ, Falase AO, Stewart S, Sliwa K. Blood pressure, the prevalence of hypertension and hypertension-related complications in Nigerian Africans: A review. World journal of cardiology. 2012 Dec 26;4(12):327.
- ↑ Aje A, Adebiyi AA, Oladapo OO, Dada A, Ogah OS, Ojji DB, Falase AO. Left ventricular geometric patterns in newly presenting Nigerian hypertensives: An echocardiographic study. BMC Cardiovascular Disorders. 2006 Dec 1;6(1):4.
- ↑ Oladapo OO, Salako L, Sadiq L, Soyinka K, Falase AO. Knowledge of hypertension and other risk factors for heart disease among Yoruba rural southwestern Nigerian population. Journal of Advances in Medicine and Medical Research. 2013 Mar 13:993-1003.
- ↑ Olubodun JO, Falase AO, Cole TO. Drug compliance in hypertensive Nigerians with and without heart failure. International journal of cardiology. 1990 May 1;27(2):229-34.
- ↑ Ojji DB, Alfa J, Ajayi SO, Mamven MH, Falase AO. Pattern of heart failure in Abuja, Nigeria: an echocardiographic study. Cardiovascular journal of Africa. 2009 Dec;20(6):349.
- ↑ Ogah OS, Stewart S, Falase AO, Akinyemi JO, Adegbite GD, Alabi AA, Ajani AA, Adesina JO, Durodola A, Sliwa K. Contemporary profile of acute heart failure in Southern Nigeria: data from the Abeokuta Heart Failure Clinical Registry. JACC: Heart Failure. 2014 Jun 1;2(3):250-9.
- ↑ Falase AO, Ayeni O, Sekoni GA, Odia OJ. Heart failure in Nigerian hypertensives. African journal of medicine and medical sciences. 1983 Mar;12(1):7-15.
- ↑ Falase AO, Cole TO, Osuntokun BO. Myocardial infarction in Nigerians. Tropical and geographical medicine. 1973;25(2):147-50.
- ↑ Falase AO, Oladapo OO, Kanu EO. Relatively low incidence of myocardial infarction in Nigerians. Cardiologie tropicale. 2001;27(107):45-7.
- ↑ Ogah OS, Adebayo O, Aje A, Koya FK, Towoju O, Adesina JO, Adeoye AM, Adebiyi AA, Oladapo OO, Falase AO. Isolated left ventricular noncompaction: Report of a case from Ibadan, Nigeria. Nigerian Journal of Cardiology. 2016 Jul 1;13(2):148.