Bisi Akin-Alabi
Bisi Akin-Alabi jẹ́ amòyé ètò ẹ̀kọ́ Nàìjíríà, oṣiṣẹ àwùjọ, alábòójútó, tẹkinọ́lọ́gì, olùdámọ̀ràn ètò ẹ̀kọ́ àti olùdámọ̀ràn pàtàkì tẹ́lẹ́ lórí ètò ẹ̀kọ́, sáyẹ́ǹsì àti ìmọ̀ èrò fún Alàgbà Abiola Ajimobi, gómìnà tẹ́lẹ̀ tí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà.[1][2][3]
Ayé àti ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bisi ní á bí ní Igbo-Ora, nìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sí bàbá Nàìjíríà tí ọ jẹ́ alámọ̀dájú atí ìyá Benin láti Porto-Novo. Ọ lọ́ sí Ilé-ìwé Federal School of Arts and Science. Ọ gbá iwé-ẹ̀kọ́ gíga tí Imọ-jinlẹ látí Yunifásítì ìlú Èkó àti Master of Business Administration látí London South Bank University.[4]
Ọ tún ní Ìwé-ẹ̀ri Postgraduate ní Ẹ̀kọ́ látí Ilé-ẹ̀kọ́ Roehampton, Ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí Surrey àti Ph.D kán ní ìdàgbàsókè ọmọdé àti àwọn ẹdá ènìyàn látí Ilé-ìwé Graduate London. Ó jẹ́ ẹ́lẹ́gbẹ́ tí International Chartered Management Consultant, Chartered Institute of Commerce of Nigeria (FCICN), Ẹ́lẹ́gbẹ́ tí Windsor Fellowship UK àti United Kingdom Strategic Society.
Ní Oṣù Kẹ́ta ọdún 2001 ní Òpópónà 10 Downing, Lọ́ńdọ́nù, ó jẹ́ ọlá fún nípasẹ Prime Minister tí Ìlú Gẹ̀ẹ́sì nigbanà, Tony Blair àti ìyàwó rẹ̀ Cherie Blair ní ìdánimọ̀ àwọn ìlọwọ́sí rẹ̀ sí ètò ẹ̀kọ́ àti ìtọ́jú ọmọ́dé ní United Kingdom.[5]
Iṣẹ́-ṣíṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bísí jẹ́ olùkọ́ ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ àti mathematics ní àwọn ilé-ìwé àkọ́kọ́ ní United Kingdom fún díẹ̀ síi jù ọdún méjì lọ́. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ SchoolRun Academy àti akédé Ìwé ìròhìn SchoolRun. Ọ jẹ́ olùdámọ̀ràn pàtàkì fún Sẹ́nẹ́tọ́ Abiola Ajimobi, gómínà tẹ́lẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Nàìjíría.
Ní ọdún 2017, ọ ṣé ágbékalẹ àwọn Ọ̀yọ́ State Model Education System Interventions, OYOMESI. Ètò náà yọrí sí gbígbà ìlú Ìbàdàn gẹ́gẹ́bí UNESCO ìlú ẹ̀kọ́.[6][7]
Áwọ́n ìtókásí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Education expert bemoans lack of commitment to community dev. initiatives - By: Adeola Badru". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-15. Retrieved 2021-06-23.
- ↑ "Foremost Ibadan education expert, Bisi Akin-Alabi to chair maiden community dev day - By: Adeola Badru". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-04. Retrieved 2021-06-23.
- ↑ "How I overcame COVID-19, by Ajimobi's ex-aide". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-01. Retrieved 2021-06-26.
- ↑ "Education festivals: Tool for supporting Nigeria's education curriculum in post-covid-19 era - By: Dayo Emmanuel". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-22. Retrieved 2021-06-23.
- ↑ Ajumobi, Kemi (2021-05-07). "Bisi Akin-Alabi, relentlessly promoting quality education in Nigeria". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-23.
- ↑ "Ibadan is UNESCO learning city ― Oyo govt". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-24. Retrieved 2021-06-23.
- ↑ "Oyo unveils new education initiative tagged 'OYOMESI'". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-05-02. Retrieved 2021-06-23.