Bolaji Aluko
Ìrísí
Professor Bolaji Aluko | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Mobolaji E. Aluko 2 Oṣù Kẹrin 1955 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ife Imperial College London University of California, Santa Barbara |
Iṣẹ́ | Engineer Academics Educational administrator |
Ìgbà iṣẹ́ | 1984–present |
Gbajúmọ̀ fún | Chemical Engineering |
Parent(s) | Sam Aluko (father) |
Àwọn olùbátan | Gbenga Aluko (brother) |
Mobolaji E. Aluko (tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù Kẹrin 1955) jẹ Ọ̀jọ̀gbọ́n tí ìmọ̀-ẹ̀rọ kẹ́míikálì ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Howard. [1] Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí alábòójútó ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti Yunifásítì Federal, Otuoke nípasẹ̀ ìjoba Àpapọ̀ti Nigeria[2] láti ọdún 2011 títí di ìpárí àkókò iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2016.[3]