Jump to content

Buchi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Onyebuchi Ojieh
PseudonymBuchi
Ìbí(1979-04-04)Oṣù Kẹrin 4, 1979
Delta State, Nigeria
Medium
  • Stand-up
  • television
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Years active2008-present
Genres
Subject(s)
Ibiìtakùnwww.buchi.tv

Onyebuchi Ojieh, tí àwọn ènìyàn mọ̀ mọ́ orúkọ orí-ìtàgé rẹ̀ Buchi (wọ́n bí i ní April 4, 1979) jẹ́ apanilẹ́rìn-ín Nàìjíríà, a-kọ-orin-sílẹ̀, òǹkọ̀wé, àti Òṣèré láti ìpínlè Delta , Nàìjíríà .[1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbé-ayé àti ẹ̀kọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Buchi ní Kwale Ndokwa West, Ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà.[2] Ó lọ D.S.C Nursery and Primary School àti Ovwian Secondary School ní Ovwian, Warri. Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ ìwé mẹ́wàá rẹ̀, ó lọ Bendel State University (tí a mọ̀ sí Ambrose Alli University ní báyìí), níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin (law).[3]

Iṣẹ́ Apanilẹ́rìn-ín

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Buchi bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ apanilẹ́rìn-ín rẹ̀ ní 2008,[4] lẹ́yìn tí wọ́n mú u mọ apanilẹ́rìn-ín Tee-A, tí ó pe Buchi sí ibi eré rẹ̀ Tee-A Live N Naked. Show ní Èkó. Èyí ló ṣáájú ìpàdé pẹ̀lú àwọn apanilẹ́rìn-ín mìíràn bí i Ali Baba àti Opa Williams, tí ó fún Buchi ní àyè ní Nite of A 1000 Laughs show rẹ̀.[5] Buchi ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn apanilẹ́rìn-ín mìíràn bí i I Go Dye, I Go Save, Basketmouth, àti Bovi, lára àwọn mìíràn .[6]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Standup Comedian Comedy of the year Youth Award Comedy of the year

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Vanguardngr (2011-12-17). "I wanted to be an Astronaut, but space is so far – Buchi". Vanguardngr. Retrieved 2011-12-17. 
  2. ireporters (2012-04-24). "News Unplugged with Buchi Nigerian Comedian". ireporters. Archived from the original on 2014-02-24. Retrieved 2012-04-24. 
  3. Vanguardngr (2014-01-04). "I still cook for my family — Buchi". Vanguardngr. Retrieved 2014-01-04. 
  4. National Daily Ng (2012-08-13). "Laffline speaks with Buchi". National Daily Ng. Archived from the original on 2014-02-21. Retrieved 2012-08-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Naijagists (2012-01-05). "Nigerian Comedian Buchi Buys Land Rover SUV". Naijagists. Retrieved 2012-01-05. 
  6. allAfrica (2012-06-02). "Buchi Nigerian Comedian in Ghana". allAfrica. Retrieved 2012-06-02.