Buka Suka Dimka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ajagun Buka Suka Dimka (ẹniti ó ṣe aláìsí ní ọj́ọ karùńdínlógún, osù karùń, ọdún 1976) j́ẹ ọmọ ogun oríléèdè Nàìjíríà. Ó kópa nínu ìgbìmọ̀ láti gba ìjọba oríléèdè Nàìjíríà lówo ̀Ọgágun Àgú̀iyí ̀Iróǹsí ní ọdún 1966. Ajagun Díḿkà sì túń kópa nínu ìgbìmọ̀ láti gba ìjoba lówo àrẹ oríléèdè, Ọgágun Murtala Ramat Mohammed ní ọj̣́o kẹtàlá, osù kejì, ọdún 1976. Ṣùgb́ọn, ìgbìm̀ọ yí k̀unọ̀ láti ṣe àseyọrí nínu gb́igba ìjọba fún ara wọn, b́i ́o ti l̀ẹ j́ẹ wípé, ìyànjú wọn ṣe ikú pa Ọgágun Murtala Ramat Mohammed.

Ẹ̀kọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ipa nínu gbígba ìjọba oríléèdè Nàìjíríà l'ọ́dún 1966[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ipa nínu gbígba ìjọba oríléèdè Nàìjíríà l'ọ́dún 1976[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

[1]

Ikú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lẹ́hìn ìgbà tí ilé ẹjọ́ àwọn ọmọ ogun oríléèdè dá Ajagun Díḿkà lẹ́ẹ̀bi, wọ́n yin ìbọn si ní ìta gbangban, ní ọj́ọ karùńdínlógún, osù karùń, ọdún 1976, l'ọ́gbà ẹ̀wọ̀n Kíríkirì, ní ìlú Èkó[2].

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Okutu, Peter. "How lust for girlfriend lured wanted Dimka to Afikpo". Vanguard. Vanguard Newspapers. Retrieved 9 October 2018. 
  2. Omoigui, Nowa. "Col. Dimka's Failed Coup Attempt". URHOBO HISTORICAL SOCIETY. URHOBO HISTORICAL SOCIETY. Retrieved 9 October 2018.