Cornelius Taiwo
Omoba Cornelius Olaleye Taiwo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oru-Ijebu Ogun State, Nigeria | 27 Oṣù Kẹ̀wá 1910
Aláìsí | 8 April 2014 Ikeja, Lagos, Nigeria | (ọmọ ọdún 103)
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Cambridge University of London |
Iṣẹ́ | Educator, lawyer, author |
Cornelius Olaleye Taiwo (tí wọ́n bí ní 27 November ọdún 1910, tí ó sì kú ní 8 April 2014) jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Nàìjíríà, tó jẹ́ onímọ̀, agbẹjọ́rò àti òǹkọ̀wé.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Taiwo ní 27 October 1910, sí Oru-Ijebu ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní Nàìjíríà, sínú ìdílé Isaac àti Lydia Taiwo.[1] Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní St. Luke's School, tó jẹ́ ilé-ìwẹ́ CMS ti St. Luke's Church lẹ́yìn ogun àgbáyé kìíní, ní Oru, Ijebu ní ọdún 1921. Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí St Andrews College, ní Oyo, kí ó ṣẹ̀ tó lọ Yaba Higher College, Lagos. Ó tún kàwé ní University of London, níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí D. Litt ní ọdún 1982. Bákan náà ni ó gba oyè M.A nínú ẹ̀kọ́ ìṣirò Mathematics láti Trinity College, Cambridge University, oyè Barrister-at-Law ní Middle Temple Inn's Court àti oyè Hon. LL.D. (Cape Coast).[2]
Ìdálọ́lá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Baba Ijo -oyè ní St. Luke's Church, ní Oru, Ijebu láti ọdún 1973.
- Fellow of Commonwealth Council for Educational Administration
- Fellow of Nigerian Academy of Education
- Lord LUPEN; NAPE's highest award (the Lord of all Luminaries of Professional Educators of Nigeria, 1989)
- Inducted into the International Educators' Hall of Fame
Àọn ìwẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lára àwọnìwé tó ti kọ ni;
- Taiwo, Cornelius O. (1976). The Mother Tongue as a Means of Promoting Equal Access to Education in Nigeria: Problems and Solutions. United Nations Educational, Scientific and Cultural Organization. https://books.google.com/books?id=ooa-tgAACAAJ.
- Taiwo, Cornelius O. (1980). 70 years in The Nigerian Educational System:past, present and future. Nelson Nigeria. ISBN 978-1260-726. https://books.google.com/books?id=pCUmYgEACAAJ.
- Taiwo, Cornelius O. (1975). Henry Carr: An African Contribution to Education. Oxford University Press. ISBN 978-0-19575-282-3. https://books.google.com/books?id=0WO7AAAAIAAJ.
- Taiwo Cornelius O.. The Education Edicts of Nigeria. 18. West African Journal of Education. pp. 183–187. http://maktaba.ku.ac.ke/cgi-bin/koha/opac-detail.pl?biblionumber=246552.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- Taiwo Cornelius O. (1976). Nigeria Language Problems and Solution. http://eric.ed.gov/?id=EJ148922.
- Taiwo Cornelius O.. The Administration and Control of Education in Nigeria.
- Taiwo Cornelius O.. Traditional Methods of Education in Africa.
- Taiwo Cornelius O.. The Rule of Law in Education.
- Taiwo, Cornelius O. (1996). Learning thrills: memoirs of an educationist. Y-Books. ISBN 9782659916. https://books.google.com/books?id=O59CAQAAIAAJ.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Deji-Folutile, Olabisi; Babalola, Ademola (27 October 2010). "100 years today...Prof. C. O. Taiwo tells his story". hoofbeat. Archived from the original on 6 January 2014. Retrieved 19 November 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Homepage". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-09.
- Àwọn àyọkà aláìní ohun-inú Wikidata
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from November 2024
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Pages with citations using unsupported parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)