Délé Giwa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Délé Giwa

Dele Giwa (16 March 1947 - 19 October 1986) Wọ́n fi lẹta tí ó ní bọ́ǹbù nínú pa Délé Giwa ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1986 nínú ilé rẹ̀ ní Èkó. Délé Giwa wà lára àwọn tí wọ́n jọ dá Newswatch magazine sílẹ̀.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]