Dakore Egbuson-Akande
Dakore Egbuson-Akande | |
---|---|
Egbuson-Akande ni AMVCA odun 2020 | |
Ọjọ́ìbí | October 14, 1978 Bayelsa State | (ọmọ ọdún 46)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | Osere |
Ìgbà iṣẹ́ | 1999 titi di bayi |
Notable work | Men do Cry |
Olólùfẹ́ | Olumide Akande 2011 titi di bayi |
Àwọn olùbátan | Timini Egbuson (omo iya) |
Dakore Egbuson-Akande (tí orúkọ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ń jẹ́ Dakore Omobola Egbuson) jẹ́ Òṣèré Nigeria.[1][2] Ó jẹ́ aṣojú fún Amnesty Internation, Amstel Malta àti Oxfam ní America.[3]
Igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìpínlẹ̀ Bàyélsà ni wọ́n bí Dakore si, gẹ́gẹ́ bíi àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀. Ó lọ sí ilé-ìwé Corona àti ilé-ìwé ìjọba Àpapọ̀ fún àwọn ọmọ obìnrin ní Ìpínlẹ̀ Èkó ati Ìpínlẹ̀ Bauchi[4] Ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ó kọ́ ìmọ̀ ìbanisọ̀rọ̀ ní Fáṣítì Èkó ṣùgbọ́n kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nitorí igbélé gbogbo ìgbà [5] Ó ti ṣe ìgbéyàwó báyìí, Ó sì ti bí ọmọ méjì[6][7]
Ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2019, wọ́n ṣe àfihàn Dakorae nínu ìwé àwòrán ti Visual Collaborative, nínu ìpele tí wọ́n pè ní Vivencias tí ó "Ìrírí" ni Èdè Spéìn. Nínu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwọ̀ pẹ̀lú àwọn ọgbọ́n ènìyàn láti oríṣiríṣi ìlú gẹ́gẹ́ bíi Kelli Ali, Adelaide Damoah àti Desdamona[8] Ní oṣù karùn-ún ọdún 2020 wọ́n tún ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwọ̀ náà gbé jáde lórí Visual Collaborative, tí wọ́n pè ní TwentyEightyFour, tí wọ́n ṣe àgbẹ́jáde rẹ̀ nígbà Àrún èrànkòrónà ọdún 2019, olórin èdè faranse Les Nubians, akọrin ti Japan Rika Muranaka àti aláwàdà ilẹ̀ Nàìjíríà Chigul jáde nínu ìpele kan náà.[9]
Asayan Ere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dakore ti ko ipa ninu fiimu ti o ju aadota lọ, diẹ ninu eyiti o pẹlu: [10]
- Peace of Flesh
- Men do Cry
- Emotional Crack
- Shattered Illusion
- When the Going gets Tough
- Playboy
- Oracle
- Hole in the Heart
- Silent Tears
- 11 days & 11 Nights
- Operation KTP
- Playboy
- Silent Tears
- Emotional Cry
- Caught in the Middle (2007)
- Journey to Self (2013)
- Lunch Time Heroes (2015)
- Fifty (2015)
- Isoken (2017)
- Chief Daddy (2018)
- New Money (2018)
- The Set Up (2019)
- Coming From Insanity
Àwọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọrí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Ayẹyẹ | Amì-ẹ̀yẹ | Ẹni tí ó gbàá | Èsì |
---|---|---|---|---|
2014 | ELOY Awards[11] | Brand Ambassador of the Year (Pampers) | N/A | Wọ́n pèé |
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "I Missed acting - Dakore". informationng.com. Retrieved 19 May 2014.
- ↑ "Dakore Egbuson is Back". punchng.com. Archived from the original on 19 May 2014. Retrieved 19 May 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Dakore reappears in Journey to Self". vanguardngr.com. Retrieved 19 May 2014.
- ↑ "Dakore Akande rocks Baby bump". thenationonlineng.net. Retrieved 19 May 2014.
- ↑ "I never prepared to be famous - Dakore Akande". modernghana.com. Retrieved 19 May 2014.
- ↑ "Becoming Mrs Akande, Dakore opens up with Life, career & motherhood". bellanaija.com. Retrieved 19 May 2014.
- ↑ "I won't romance & kiss anymore in films - Dakore". dailystar.com.ng. Archived from the original on 19 May 2014. Retrieved 19 May 2014.
- ↑ "Dakore Egbuson-Akande, Swaady Martin, others catalogued in Vicencias". June 19, 2019. Archived from the original on 2019-11-14. Retrieved September 7, 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Onyekwelu, Stephen (6 May 2020). "Les Nubians, Rika, Chigul, Dakore feature in TwentyEightyFour". Business Day (Nigeria). https://businessday.ng/life-arts/article/les-nubians-rika-chigul-dakore-feature-in-twentyeightyfour/. Retrieved 15 May 2020.
- ↑ "Dakore Akande on IROKOtv". irokotv.com. Archived from the original on 19 May 2014. Retrieved 19 May 2014.
- ↑ "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 20 October 2014.