Timini Egbuson
Timini Egbuson | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | James Timini Egbuson June 10, 1987 (ọmọ ọdún 37) Bayelsa State, Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2009-present |
Gbajúmọ̀ fún | Elevator Baby, Shuga, Fifty, Skinny Girl in Transit, Manhunting with Mum, Tinsel ,Sophia |
Àwọn olùbátan | Dakore Àkàndé (sister) |
Website | timiniegbuson.com |
Timini Egbuson Tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹwàá oṣù Kẹfà ọdún 1987, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde àti olùàiṣẹ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára. [1]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Timini ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa, ó jẹ́ àbúrò fún gbajú-gbajà òṣèré Dakore Egbuson Àkàndé.[2] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Greenspring Montessori, The Afro School and St Catherine's. Ó tún l9 sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Adebayo Mokuolu College ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó kàwé gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Psychology ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Ìpínlẹ̀ Èkó.[3] Ó sì jáde ní ọdún 2011. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé ṣíṣe ní ọdún 2010 nígbà rtí ó kópa nínú eré onípele àtìgbà-dégbà ti Tinsel. Timini gba amì-ẹ̀yẹ ti AMVCA awards fún Òṣèrékúnrin tí ó peregedé jùlọ 0àá pàá jùlọ fún ipa tí ó kó nínú eré Elevator baby.[4]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Timini ti kópa nínú àwọn eré tí ó ti pọ̀ [5]
- "MTv Shuga"
- "Fifty"
- "Skinny Girl in Transit"
- "Manhunting with Mum"
- "Tinsel"
- "Fifty the series"
- "Isoken"
- "Something Wicked"
- "Another Time"
- "Room 420"
- "Ajuwaya"
- "the missing piece"
- "the intern"
- "Elevator Baby"
- "The girl code"
Awards and Nominations
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Event | Prize | Result | ||
---|---|---|---|---|---|
2017 | City People Award[6] | Best New Actor of the year | Nominated | ||
2019 | The Future Awards Africa | Prize for Acting | Won | ||
2020 | AMVCA awards[4] | Best Actor in a Drama(Movie/TV series) | Won |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Timini Egbuson: Biography And Success Journey Of Nollywood's Finest". Entrepreneurs. 2019-10-20. Retrieved 2020-11-03.
- ↑ "Timini Egbuson Biography and Profile - Nairagent.com". Naira Gent. 2019-09-22. Archived from the original on 2020-06-09. Retrieved 2020-11-03.
- ↑ "WHO IS TIMINI EGBUSON? BIOGRAPHY/PROFILE/HISTORY OF NOLLYWOOD ACTOR TIMINI EGBUSON". dailymedia.com. Daily Media. Archived from the original on 2017-12-19. Retrieved 2020-11-03.
- ↑ 4.0 4.1 "Africa! Here Are Your Winners at the 7th AMVCAs". Africa Magic - Africa! Here Are Your Winners at the 7th AMVCAs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-23.
- ↑ "Timini Egbuson on IMBd".
- ↑ "City People Releases Nomination List For 2017 Movie Awards - City People Magazine". citypeopleonline.com. 8 September 2017.