Jump to content

Draw soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Draw soup
Okro soup
Alternative namesOkra soup
TypeSoup
Main ingredientsOkra, ogbono seeds or ewedu leaves
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Ọbẹ̀ẹ́yọ̀ jẹ́ orúkọ àwọn ọbẹ̀ ní Gúúsù ìlàòrùn àti Gúúsù ìwọ̀òrùn Nàìjíríà[1] tí a fi ilá, ọ̀gbọ̀nọ̀ (Irvingia gabonensis), tàbí ewédú sè.[2] Orúkọ ọbẹ̀ yíì wá láti bí ọbẹ̀ náà ṣe ki tí ó sì tún fà nínú àwo nígbà tí a bá ń jẹ ẹ́tàbí nígbà tí a bá ń fi ọ̀kèlè bíi(fùfú[3] ijẹ ẹ́ IA lè fi orísìírísìí òkèlè jẹ ẹ́ eíi ba (garri) aàtipiyán Ewwédú [4] ṣe é fi se ọ̀bẹ̀ Yorùbá tí a máa ń jẹ pẹ̀lú Àmàlà.

bésẹ̀ sísèg Àwọn èrọ̀jà ọbẹ̀ẹ́yọ̀ ni:

  • Ilá
  • Ọ̀gbọ̀nọ̀[5] (wọ̀fún)
  • Ẹ̀fọ́ Ugu
  • Ewé Uziza
  • Irú
  • Ata
  • Edé[6]
  • Ogiri okpei (wọ̀fún)[5]
  • Ẹran
  • Ẹja
  • Epo pupa[7]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ImmaculateBites (2022-04-06). "Ogbono Soup". Immaculate Bites (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31. 
  2. "How To Cook Ogbono Soup | Nigerian Draw Soup Recipe". All Nigerian Foods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31. 
  3. "fufu | food | Britannica". www.britannica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31. 
  4. "Ewedu - Jute Leaves Soup". Chef Lola's Kitchen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-03-05. Retrieved 2022-08-31. 
  5. 5.0 5.1 vanguard (2019-06-13). "Traditional dishes going into extinction are back". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31. 
  6. ""By Their Foods, Ye Shall Know Them"". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-03. Archived from the original on 2022-09-24. Retrieved 2022-08-31. 
  7. Rapheal (2018-05-31). "Which oil is best for you? (1)". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-31. 

Àdàkọ:African cuisine

Àdàkọ:Nigeria-cuisine-stub Àdàkọ:Soup-stub