Jump to content

Ebele Okaro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
ÌbíLondon, United Kingdom
Iṣẹ́Òṣèré

Ebele Okaro Onyiuke jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà [1] [2]

Ìgbé ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Okaro ní ìlú Lọ́ndònù, wọ́n sì tọ dàgbà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ìpínlẹ̀ Enugu.[3] Ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣeré orí-ìtàgé láti ìgbà tí ó ti wà ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ " Santa Maria Primary School".[1][2] ti ́ó sì tẹ̀ síwájú nínú eré rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ Nsukka's Queen of the Holy Rosary Secondary School. Lẹ́yìn tí ó parí, ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásitì Calabar láti kọ́ nípa ìmọ̀ ìkọ́ni,. Okaro dara pọ̀ mọ́ àwọn eléré oníṣe orí ìtàgé lẹ́yin tí ó kàwé gboyè tán.[2][3] Her mother was a full-time television producer and her father was an engineer[4] who had great interest in arts and literature.

Lẹ́yìn tí ó jáde Fásitì tán, tí ó sì ṣe àgùnbánirọ̀ rẹ̀ tạn ní ilé-iṣẹ́ amóhùn-máwòrán NTA, ibẹ̀ ni ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ìfẹ́ sí ṣíṣe iṣẹ́ lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán [2][4] Bákan náà, ó ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ tí ó ń rí sí ìrìnà lọ sí òkè òkun ní ìpínlẹ̀ Èkó, ṣáájú kí ó tó padà sí ẹnu iṣẹ́ eré ṣíṣe.[3] Ní ọdún 2014, Ebele Okaro Onyiuke gbé eré kan jáde tí ó pè ní Musical Whispers, eré tí ó ké gbàjarè fún ìtọ́jú àwọn ọmọ tí wọ́n ní àìsànautism.[5][6][7] It features other prominent Nigerian actors and actresses, most notably Chioma Chukwuka and Kalu Ikeagwu.[6] Látàrí eré yí, wọ́n fun ní àlàjẹ́ "Mama of Nollywood"[1][4].[3]

Òun àti ẹbí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó lọ́kọ sí ìdílé Onyiuke.[3]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òun ni ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti African Magic Viewers Choice Award In 2017, her performance in 4-1 Love won Okaro the for Best Supporting Actress.[3][8] She was nominated for her rolei the movie 'Smash' at 2020 Africa Magic Viewers' Choice Awards for Best Actress in a Comedy (Movie/TV Series).[9]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Ipa tí ó kó Adar eré Notes References
Eziza [4][3]
Moving Fingers [4][3]
Red Light [3]
Shallow Waters [3]
Third Eye [4][3]
1996 Hostages Tádé Ògìdán [4][3][10]
2006 30 Days Mama Alero Mildred Okwo [4][3][11]
2014 Bambitious Dr. Ese Okechukwu Oku [12]
2014 Chetanna Ikechukwu Onyeka Igbo language [13]
2014 Musical Whispers Jasmine Bond Emerua Also the producer [5][6]
2016 4-1-Love Uju's Mother Ikechukwu Onyeka Best Supporting Actress in a Drama – 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards [3]
2015 The Powerful Babies Chioma [citation needed]
2017 Karma Mama Ngozi Mayor Ofoegbu [14]
2019 Living in Bondage: Breaking Free Eunice Nworie Ramsey Nouah

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 "Actress Ebele Okaro Stuns in New Birthday Photos". gistmynaija.com. 19 January 2016. Archived from the original on 8 November 2020. Retrieved 13 May 2017. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Ebere Okaro". 30 May 2007. https://www.modernghana.com/movie/1221/3/ebere-okaro.html. Retrieved 4 April 2017. 
  3. 3.00 3.01 3.02 3.03 3.04 3.05 3.06 3.07 3.08 3.09 3.10 3.11 3.12 3.13 Husseini, Shaibu (18 March 2017). "Avpip for beloved Nollywood actress, Ebele Okaro-Onyiuke". The Guardian. Archived from the original on 23 March 2017. https://web.archive.org/web/20170323073226/http://guardian.ng/saturday-magazine/a-pip-for-beloved-nollywood-actress-ebele-okaro-onyiuke/. Retrieved 13 May 2017. 
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 4.4 4.5 4.6 4.7 Williams, Yvonne (19 January 2016). "Birthday Shout! Celebrating veteran Nollywood actress Ebele Okaro". Happenings Magazine. Archived from the original on 8 April 2017. https://web.archive.org/web/20170408081427/http://happenings.com.ng/birthday-shout-celebrating-veteran-nollywood-actress-ebele-okaro/. 
  5. 5.0 5.1 Dachen, Isaac (14 May 2014). "She Is Back: Veteran Actress, Ebele Okaro Makes Return In Musical Whispers". http://pulse.ng/movies/she-is-back-veteran-actress-ebele-okaro-makes-return-in-musical-whispers-id2851288.html. Retrieved 4 April 2017. 
  6. 6.0 6.1 6.2 Elekwachi, Edith (16 May 2014). "Nollywood Thespian Ebele Okaro-Onyiuke Debuts New Movie Against 'Autism'". https://www.modernghana.com/movie/28662/3/nollywood-thespian-ebele-okaro-onyiuke-debuts-new-movie-against-autism.html. Retrieved 6 April 2017. 
  7. "Nigeria: Okaro-Onyiuke's Autism-Inspired Musical Whispers Premieres With Glam". The Daily Independent. 6 June 2014. http://allafrica.com/stories/201406060940.html. Retrieved 4 April 2017. 
  8. Inyang, Ifreke (5 March 2017). "'76' wins five awards at AMVCA 2017". Daily Post. http://dailypost.ng/2017/03/05/76-wins-five-awards-amvca-2017-see-full-list-winners/. Retrieved 6 April 2017. 
  9. "2020 AMVCA: Check out the full nominees’ list". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-07. Retrieved 2020-10-10. 
  10. "Film: OGD Pictures Limited – Television & Film Production". OGD Pictures Limited. 2011. Archived from the original on 7 April 2017. Retrieved 7 April 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. Osofisan, Sola (30 July 2006). "Does 30 Days Live Up To The Hype?". nigeriansinamerica.com. Retrieved 13 May 2017. 
  12. Izuzu, Chidumga (2 December 2014). "'Bambitious': Daniel K Daniel, Belinda Effah, Selebobo attend Enugu premiere". http://pulse.ng/movies/bambitious-daniel-k-daniel-belinda-effah-selebobo-attend-enugu-premiere-id3316740.html. Retrieved 13 May 2017. 
  13. Izuzu, Chidumga (29 October 2014). "'Chetanna': Chigozie Atuanya's Movie Wins Best Indigenous Film". http://pulse.ng/movies/chetanna-chigozie-atuanyas-movie-wins-best-indigenous-film-id3232472.html. Retrieved 13 May 2017. 
  14. "Road To Yesterday For Release November 27". The Guardian. 31 October 2015. http://guardian.ng/saturday-magazine/road-to-yesterday-for-release-november-27/. Retrieved 13 May 2017. 

Àdàkọ:Authority control