Erékùṣù Robben
Erékùṣù Robben Robben Island* | |
---|---|
Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé UNESCO | |
Prison buildings on Robben Island. Table Mountain is visible 15 km in the background | |
State Party | Gúúsù Áfríkà |
Type | Cultural |
Criteria | iii, vi |
Reference | 916 |
Region** | Africa |
Coordinates | 33°48′24″S 18°21′58″E / 33.806734°S 18.366222°ECoordinates: 33°48′24″S 18°21′58″E / 33.806734°S 18.366222°E |
Inscription history | |
Inscription | 1999 (23rd Session) |
* Name as inscribed on World Heritage List. ** Region as classified by UNESCO. |
Erékùṣù Robben (Geesi: Robben Island; Afrikaans Robbeneiland) je erekusu ni Table Bay, to je kilomita meje leba Cape Town, ni Guusu Afrika. O je ede Dọ́tsh fun "seal island". Erekusu Robben ri bi oval, 3.3 km gigun lati ariwa de guusu, ati 1.9 km ni fife, pelu aala to je 5.07 km².[1] Pelebe ni, o si je bi mita melo soke ipele omi-okun, nitori agbara-omi to sele nigba ijoun. O kun fun awon okuta ateyinda igba Atetesi Kambria ninu Adipo Malmesbury Group. Erekusu yi se pataki nitoripe ibe ni Aare ile Guusu Afrika ojowaju ati Elebun Nobel Nelson Mandela ati Aare ile Guusu Afrika ojowaju Kgalema Motlanthe,[2] bakanna mo awon elewon oloselu miran, ti lo igba ewon won ni asiko apartheid. Jacob Zuma to je Aare ile Guusu Afrika tẹlẹ na lo odun mewa nibe bi elewon.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "?".
- ↑ "New S. Africa president sworn in". BBC News. 2008-09-25. Retrieved 2008-11-22.