Esther Ijewere-Kalejaiye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Esther Ijewere- Kalejaiye
IbùgbéÌlú Èkó, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèỌmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Iṣẹ́Akọ̀wé àti Ajìjàgbra
Gbajúmọ̀ fúnÌwé kíkọ̀ àti Walk Against Rape
TitleAláṣẹ àti Olùdarí

Esther Ijewere-Kalejaiye jẹ́ olùkọ̀wé obìnrin ọmọ Nàíjír̀a, alágbàwí, onígbèjà àwọn obìrin àti àwọn ̣ọmọdébìrin àti akọrọ̀yìn ní Ilé-ìròhìn The Guardian.

Ìgbésíayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó kàwégboyè nínú ìmọ̀ Sociology láti Olabisi Onabanjo University, Àgó-Íwòyè, Ogun State, Nàìj́írìa,[1] Ijewere-Kalejaiye ni olùdásílẹ̀ Rubies Ink Initiative fún àwọn obìrin àti ọmọdé, Ilé-iṣẹ́ tí ńṣe agbọ̀rọ̀dùn fún àwọn obìnrin àti ọmọdébìrin pẹ̀lú Walk Against Rape, Women of Rubies, Project Capable, Rubies Ink Media àti College Acquaintance Rape Education Workshop.[2] Ní ọdún 2013, Ìjàgbara rẹ̀ láti lè dojú ìjà kọ ìfi ípa bá obìnrin lò mu u kọ ìwé Breaking the Silence, ìwé tí on filọ̀ nípa ìfi ípa bá obìnrin lò àti okùnfà rẹ̀.[3] Àwọn ojúṣe rẹ̀ sí àwùjọ Nàìj́írìa ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ àti Ilé-iṣẹ́ ̀Ijọba ní wọ́n tí ṣe ìránt́i rẹ.[4] Ní ọjọ́ kẹsan oṣù keje ọdún 2016, wọ́n fún ní ẹ̀bùn “Young Person of the Year Award” ní Miss Tourism Nigeria beauty pageant ti ọdún 2016 .[5] Ó tún gba ẹ̀bùn Wise Women Awards ti "Christian Woman in Media Award" tí ó gba nínú osù kẹfà nínú odún 2016.[6] Ijewere-Kalejaiye tí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lu ọmọ méjì.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]