Ewúrẹ́
Ìrísí
Ewúrẹ́ | |
---|---|
A pygmy goat on a stump | |
Ipò ìdasí | |
Ọ̀sìn
| |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Ìjọba: | Animalia (Àwọn ẹranko) |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ) |
Ìtò: | Oníka-dídọ́gba |
Ìdílé: | Bovidae |
Subfamily: | Caprinae |
Ìbátan: | Capra (genus) |
Irú: | |
Irú-ọmọ: | C. a. hircus
|
Ìfúnlórúkọ mẹ́ta | |
Capra aegagrus hircus | |
Synonyms | |
Capra hircus Linnaeus, 1758 |
Ewúrẹ́ jẹ́ ẹran ọ̀sìn ilé [1] tí ó jẹ́ olóri kunkun, ẹranko yí a sì máa dùn lọ́bẹ̀.
Orísi ewúrẹ́ tí ó wà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oríṣiríṣi ni eran ewúrẹ́ káàkiri agbáyé, amọ́ irúfẹ́ Oríṣi tí kò bàá jẹ́ takọ tabo ni wọ́n wà. Akọ ewúrẹ́ ni ni a ń pè ní òbúkọ nígbà tí abo ewúrẹ́ jẹ́ ewúrẹ́.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bradford, Alina (2015-10-21). "Facts About Goats". livescience.com. Retrieved 2020-08-21.