Fémi Pedro
Ìrísí
Femi Pedro | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Olufemi Olusegun Pedro 29 Oṣù Kínní 1955 Lagos Island, Lagos State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Wisconsin Wichita State University |
Iṣẹ́ | Politician Banker |
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–present |
Political party | All Progressives Congress |
Olólùfẹ́ | Hon. Justice Jumoke Pedro |
Olúfẹ́mi "Fémi" Pedro (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kìnínní ọdún 1955 ni Ilu Eko) tí fìgbà kan jẹ́ Igbákejì Gómìnà ti Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà latí ọdún 2003 títí di ọdún 2007. Kí a tó dìbò yàn án pẹ̀lú Bọ́lá Tinúbú, ó jẹ́ ó̀gá àgbà ilé-iṣẹ́ àti ọ̀kan lára àwọn òlùdásílẹ̀ ilé-iṣé First Atlantic Bank, tí a mọ̀ sí FinBank báyìí
Ní báyìí, Fẹ́mi Pedro jẹ́ Alága fún ilé-iṣẹ́ Ìjọba tó ń rí sí ìdàgbàsókè okowò pẹ́pẹ̀pẹ́ (Small and Medium Enterprise Development Agency of Nigeria, SMEDAN), ó sìn tún jẹ́ Alága àkọ́kọ́ fún Ẹ̀ka Ilé-iṣẹ́ ìkówójọ fún Eré-Ìdárayá ní Ìpínlẹ̀ Èkó (Lagos State Sports Trust Fund.)