Fati Lami Abubakar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hon

Fatima Lami Abubakar
Adájọ́ àgbà fún Ìpínlẹ̀ Niger
In office
March 2013 – April 2016
AsíwájúHon. Justice Jibrin Ndajiwo
Obìnrin àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà àti Aya Ààrẹ-àná lọ́dún 1998 sí 1999
In office
June 1998 – May 1999
ÀàrẹAbdulsalami Abubakar
AsíwájúMaryam Abacha
Arọ́pòStella Obasanjo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Fatima Lami

12 Oṣù Kẹrin 1951 (1951-04-12) (ọmọ ọdún 72)
Minna, Nigeria
(Àwọn) olólùfẹ́Abdulsalami Abubakar
Àwọn ọmọSix

Fati Lami Abubakar tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 (12 April 1951) jẹ́ Adájọ́ àgbà Ìpínlẹ̀ Niger, Obìnrin àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà àti Aya Ààrẹ-àná, Abdulsalami Abubakar lọ́dún 1998 sí 1999. Ó di Adájọ́ àgbà ní Ìpínlẹ̀ Niger lọ́dún 2013 sí 2016.

Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Fati lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 ní ìlú Minna, ní [[Ìpínlẹ̀ Niger] [lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ó kàwé ni Queen Elizabeth School ní [[Ilorin], ní Ìpínlẹ̀ Kwara.[1] Bẹ́ẹ̀ náà, ó kàwé ní Federal Government College, ní Ìpínlẹ̀ Sokoto, àti ní Obafemi Awolowo University, Ilé Ifẹ̀, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin, bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè ọ̀mọ̀wẹ́ nínú ìmọ̀ Philosophy.[2] Bákan náà, Fati kàwé gboyè ní 'Nigeria Law School'.[1]

Ìgbésí ayé rẹ̀ lọ́tọ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fati Lami fẹ́ Àárẹ̀ àná, Abdulsalami Abubakar, wọn sìn bí ọmọ mẹ́fà fún ara wọn.[3]

Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abubakar ti fẹ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí, Abdulsalami Abubakar, ẹni tí ó bí ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú. [4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]