Jump to content

Fatimah Muhammad Lolo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Nigerian English

Hajiya Fatima Lolo
Orúkọ àbísọFatima Muhammadu Kolo
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiFatima Lolo
Ọjọ́ìbí(1891-01-19)19 Oṣù Kínní 1891
Pategi, Royal Niger Company, Colonial Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Northern Region, Nigeria
Aláìsí15 May 1997(1997-05-15) (ọmọ ọdún 106)
Niger State
Irú orinSoul, R&B, local singer, Nupe local singer
OccupationsTraditional singer
Awards: (MON)

Hajiya Fatima Lolo (MON), (wọ́n bí Fatima Muhammad Kolo ní Pategi, Royal Niger Company; Ọjọ́ kọkọ̀ndílógún oṣù kìíní Ọdún 1891. Ó fi ayé lè ní Ọjọ́ Kọkọ̀ndílógún Oṣù karùn-ún Ọdún 1997) ó jẹ́ Akọrin àti Òpìtàn ìlú Nàìjíríà.

.[1]

Lolo fẹ́ àwọn ènìyàn méjì tẹ́lẹ̀ rí tí ò sì rí ọmọ bí ní àwọn ìgbéyàwó méjèèjì. Ó máa ń ṣe aṣojú fún Nupe Kingdom Emirate ní àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Ọdún àti àwọn Àjọyọ̀ wọn. Kó tó gbajúmọ, ó máa ń kọrin fún àwọn Àgbẹ̀ àti àwọn Ọdẹ. Nígbà náà tó bá ń jó, abọ́ máa ń wà lọ́wọ́ rẹ̀. Lẹ́yìn ìgbà náà ni àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ sí Sagi Ningbazi (Olórí àwọn Olórin) ní Èdè Nupe. Ó gba Oyè MON Member of the Order of the Niger láti ọwọ́ Shehu Shagari.[2]

Lolo kú ní ọmọ-ọdún mẹ́fà-lé-ní-Ọgọ́rùn-ún ní Ọjọ́ Ọjọ́ Kọkọ̀ndílógún Oṣù karùn-ún Ọdún 1997, lẹ́yìn àìsàn ráńpẹ́ tó ṣe é.[citation needed]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Akande, Jadesola Olayinka Debo (1990). The Contribution of Women to National Development in Nigeria. Nigerian Association of University Women. p. 4,62, 63. ISBN 9789783065000. https://books.google.com/books?id=EuC0AAAAIAAJ. 
  2. Book Now "World Nupe singer Hajiya Fatima Biography" [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], Book Now Ng, 2019