Jump to content

Femi Kuti

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Femi Kuti
Photo by Tom Beetz
Photo by Tom Beetz
Background information
Orúkọ àbísọFemi Anikulapo Kuti
Ìbẹ̀rẹ̀London, UK/Nigeria
Irú orinAfrobeat, jazz
Occupation(s)Singer-songwriter, instrumentalist
InstrumentsSaxophone, vocals, trumpet, keyboards
Years active1978 - present
Associated actsEgypt 80, Positive Force

Olúfẹlá Olúfẹ́mi Aníkúlápó Kútì (ọjọ́ìbí 16 June 1962) jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria. Gbajúgbajà akọrin yí ni a mọ̀ sí Fẹ́mi Kútì. Ó jẹ́ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a bí ní ìlú London tí ó dàgbà sí ìlú Èkó. Ó jé àkọ́bí ọmọ ọkùnrin ọmọ bíbí olùdásílẹ̀ orin Afrobeat tí a mọ̀ sí Fẹlá Kútì àti ọmọ ọmọ akíkanjú olóṣèlú, ajá fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin, ìyá ààfin Olúfúnmiláyọ̀ Ransome-Kútí.Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]