Folasade Ogunsola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Folasade Ogunsola
Adarí kẹtàlá Yunifásitì ìlú Èkó
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
12 November 2022
AsíwájúOluwatoyin Ogundipe
Deputy Vice Chancellor (Development Services), University of Lagos
In office
2017–2021
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Folasade Tolulope Mabogunje

1958 (ọmọ ọdún 65–66)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Alma materCollege of Medicine, Unilag
(Masters in Medical microbiology)
College of Medicine, University of Wales, Cardiff
(Doctor of Philosophy in Medical microbiology)

Folashade Tolúlọpẹ́ Ògúnṣọlá ẹni tí wọ́n bí ní ọdún 1958 jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Medical Microbiology, òun sì ni Alákòóso àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì ìlú Èkó lásìkò tí a ń kọ àpilẹ̀kọ yí.[1] Ó jẹ́ onímọ̀ nípa bí a ń kojú àrùn pàá pàá jùlọ kòkòrò àrùnHIV/AIDs. Ògúnṣọla ti kọ́kọ́ di ipò Alákòóso agbà (Provosti) ti ilé-ẹ̀kọ́ imọ̀ ìṣègùn oyinbo ti (College of Medicine) ti Yunifásitì ìlú Eko mú rí, òun sì ni obìnrin akọ́kọ́ tí o kọ́kó di ipò náà mú. Ó tún wà lára àwọn ígbákejì adarí ti Yunifásitì náà, ipò ti o di mú láàrín ọdún 2017 sí ọdún 2021.[2] A fi si adilemu ipò adari Yunifásitì ìpínlè Èkó ni ojo kerinlelogun osu Kejo(24 August) odun 2020) léyìn igba ti won yo Òjògbón Oluwatoyin Ogundipe ni ipò adari ilé-ìwé náà. Ni ojo keje osu kewa(7 Oct 2022), a yan Ogunshola gégé bi adari ilé-ìwé náà, oun si ni obinrin àkókó ti o di ipò náà mu.[3]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n tọ́ Ògúnṣọlá dàgbà nínú ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì ìlú Ibadan níbi tí bàbá rè, Akin Maábògùnjẹ́ ti jẹ́ olùkọ́.[4] Nígba ti ó wà ni omodé, o ma ń ṣe bi àwọn onímò òyìnbó pẹ́lú bí ó ṣe ma ń fi àwọn bèbí ìṣeré ọmọdé ṣeré, tí ó sì ma ń ṣe bí ẹni wípé òun ń ṣe itọ́jú wọn.

Ó lo ilé-ìwé Queen's College, ìpinlè Èkó.[5] Ni arin odún 1974 si odun 1982, o gbà àmì-èye àkókó rè ni Yunifásitì ìlú Ifè[6] ati àmì-èye Master degree rè ní College of Medicine ti yunifásitì ìlú Eko, o si tún tesiwaju láti gba àmì-èye doctorate rè ni Yunifásitì ìlú Wales larin odun 1992 si 1997.[7]

Isé rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A yan Ogunshola láti se adilemu ipò adari yunifásitì ìpinlè Eko fun ìgbà dí è ni odun 2020 nígbà ti wahala be sile ni ilé-ìwé náà nitori pé awon alaga ilé-ìwé náà yo adari rè. Ó tun wa lára awon ígbákejì adari ilé-ìwé náà, ki o to di pé o di adilemu ipo adari rè.[8]. Kí ó tó dé ipò òkan lara àwon ígbákejì adari ilé-ìwé náà, óun ni provosti ilé-ìwé ìmò òyìnbó(College of Medicine).

Awon iwádí re wa lori bi a ti ún koju àwon àárun ti Virusi fa. Oun ni oludari awadi àjo AIDS Prevention Initiative in Nigeria(APIN) ni Yunifásitì ìlú Eko, oun tun ni alaga àjo Infection Control Committee ti Teaching Hospital ìpinlè Eko(LUTH). Ogunshola tun jé alaga National Association of Colleges of Medicine in Nigeria.[9]

Ni odun 2018, o soro lori ero rè nípa kíkojú aarun ni Nàìjíríà. O ni aini imototo àti ilo ogun Antibiotics ju botiye lo wa lara idi ti ògùn apa àárun o fi ka àwon kokoro to un fa aàrùn mó. O wà lara omo egbé àkókò ti egbé Nigerian Society for Infection control ní odun 1998 o si wa lara àwon omo egbé Global Infection Prevention and Control Network.[10]

Àwon ìwé àti àtèjáde rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Modification of a PCR Ribotyping Method for Application as a Routine Typing Scheme for Clostridium difficile, 1996[11]
  • Infections caused by Acinetobacter species and their susceptibility to 14 antibiotics in Lagos University Teaching Hospital, Lagos, 2002[12]
  • Attitudes of Health Care Providers to Persons Living with HIV/AIDS in Lagos State, Nigeria, 2003[13]
  • Extended-Spectrum β-Lactamase Enzymes in Clinical Isolates of Enterobacter Species from Lagos, Nigeria, 2003[14]
  • Risk factors for ectopic pregnancy in Lagos, Nigeria, 2005[15]
  • Challenges for the sexual health and social acceptance of men who have sex with men in Nigeria, 2007[16]
  • Associated risk factors and pulsed field gel electrophoresis of nasal isolates of Staphylococcus aureus from medical students in a tertiary hospital in Lagos, Nigeria, 2007[17]
  • Effectiveness of cellulose sulfate vaginal gel for the prevention of HIV infection: results of a Phase III trial in Nigeria, 2008[18]
  • The effects of antimicrobial therapy on bacterial vaginosis in non‐pregnant women, 2009[19]
  • Antimicrobial susceptibility and serovars of Salmonella from chickens and humans in Ibadan, Nigeria, 2010[20]
  • Characterization of methicillin-susceptible and -resistant staphylococci in the clinical setting: a multi-centre study in Nigeria, 2012[21]
  • A community-engaged infection prevention and control approach to Ebola, 2015[22]

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Breaking: Unilag Gets First Female VC, Prof. Folasade Ogunsola Named New Head of 60-year-old Institution – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. October 7, 2022. Retrieved October 8, 2022. 
  2. ""What I do deals with internationalization, entrepreneurship and strategic planning..." - DVC DS UNILAG". UNILAG NEWS. July 24, 2018. Archived from the original on October 7, 2022. Retrieved October 8, 2022. 
  3. Jeremiah, Urowayino (October 7, 2022). "Folasade Ogunsola emerges UNILAG's first female VC". Vanguard News. Retrieved October 8, 2022. 
  4. Online, Tribune (August 24, 2020). "10 things to know about Prof Folashade Ogunsola, UNILAG Acting VC". Tribune Online. Retrieved October 8, 2022. 
  5. "QC unveils Hall of Fame, solar water project". Vanguard News. December 14, 2016. Retrieved October 8, 2022. 
  6. "Dr Folasade T. Ogunsola". LUTH. Archived from the original on 2019-07-01. Retrieved 2022-10-08. 
  7. "I never knew I could be professor of microbiology, my least favourite course in school –Folasade Ogunsola, DVC, UNILAG". Punch. August 18, 2018. 
  8. Nation, The (November 12, 2020). "Unilag: Ogundipe, reinstated VC returns, addresses cheerful crowd The Nation Newspaper". The Nation Newspaper. Retrieved October 8, 2022. 
  9. Awosiyan, Kunle. "16 Prominent Nigerian Women That Excel In Science And Research". Silverbird TV. Archived from the original on 2019-07-07. Retrieved 2022-10-08. 
  10. "Short Biography of Folashade Ogunsola" (PDF). WHO. 
  11. O'Neill, G. L.; Ogunsola, F. T.; Brazier, J. S.; Duerden, B. I. (1996-08-01). "Modification of a PCR Ribotyping Method for Application as a Routine Typing Scheme for Clostridium difficile" (in en). Anaerobe 2 (4): 205–209. doi:10.1006/anae.1996.0028. ISSN 1075-9964. https://www.sciencedirect.com/science/article/pii/S1075996496900281. 
  12. Iregbu, K. C.; Ogunsola, F. T.; Odugbemi, T. O. (2002). "Infections caused by Acinetobacter species and their susceptibility to 14 antibiotics in Lagos University Teaching Hospital, Lagos" (in en). West African Journal of Medicine 21 (3): 226–229. doi:10.4314/wajm.v21i3.28036. ISSN 0189-160X. PMID 12744574. https://www.ajol.info/index.php/wajm/article/view/28036. 
  13. Adebajo, Sylvia Bolanle; Bamgbala, Abisola O.; Oyediran, Muriel A. (2003). "Attitudes of Health Care Providers to Persons Living with HIV/AIDS in Lagos State, Nigeria". African Journal of Reproductive Health 7 (1): 103–112. doi:10.2307/3583350. ISSN 1118-4841. JSTOR 3583350. PMID 12816317. https://www.jstor.org/stable/3583350. 
  14. Aibinu, I. E.; Ohaegbulam, V. C.; Adenipekun, E. A.; Ogunsola, F. T.; Odugbemi, T. O.; Mee, B. J. (2003-05-01). "Extended-Spectrum β-Lactamase Enzymes in Clinical Isolates of Enterobacter Species from Lagos, Nigeria" (in en). Journal of Clinical Microbiology 41 (5): 2197–2200. doi:10.1128/JCM.41.5.2197-2200.2003. ISSN 0095-1137. PMC 154721. PMID 12734278. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=154721. 
  15. Anorlu, Rose I.; Oluwole, Ayodeji; Abudu, Olalekan Olantunji; Adebajo, Sylvia (February 2005). "Risk factors for ectopic pregnancy in Lagos, Nigeria: Risk factors for ectopic pregnancy in Lagos" (in en). Acta Obstetricia et Gynecologica Scandinavica 84 (2): 184–188. doi:10.1111/j.0001-6349.2005.00684.x. PMID 15683381. http://doi.wiley.com/10.1111/j.0001-6349.2005.00684.x. 
  16. Allman, Dan; Adebajo, Sylvia; Myers, Ted; Odumuye, Oludare; Ogunsola, Sade (2007-03-01). "Challenges for the sexual health and social acceptance of men who have sex with men in Nigeria". Culture, Health & Sexuality 9 (2): 153–168. doi:10.1080/13691050601040480. ISSN 1369-1058. PMID 17364723. https://doi.org/10.1080/13691050601040480. 
  17. Adesida, Solayide A.; Abioye, Olusegun A.; Bamiro, Babajide S.; Brai, Bartholomew I. C.; Smith, Stella I.; Amisu, Kehinde O.; Ehichioya, Deborah U.; Ogunsola, Folasade T. et al. (February 2007). "Associated risk factors and pulsed field gel electrophoresis of nasal isolates of Staphylococcus aureus from medical students in a tertiary hospital in Lagos, Nigeria". Brazilian Journal of Infectious Diseases 11 (1): 63–69. doi:10.1590/S1413-86702007000100016. ISSN 1413-8670. PMID 17625730. 
  18. Halpern, Vera; Ogunsola, Folasade; Obunge, Orikomaba; Wang, Chin-Hua; Onyejepu, Nneka; Oduyebo, Oyinola; Taylor, Doug; McNeil, Linda et al. (2008-11-21). "Effectiveness of Cellulose Sulfate Vaginal Gel for the Prevention of HIV Infection: Results of a Phase III Trial in Nigeria" (in en). PLOS ONE 3 (11): e3784. Bibcode 2008PLoSO...3.3784H. doi:10.1371/journal.pone.0003784. ISSN 1932-6203. PMC 2582655. PMID 19023429. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2582655. 
  19. Oduyebo, Oyinlola O; Anorlu, Rose I; Ogunsola, Folasade T (2009-07-08). Cochrane STI Group. ed. "The effects of antimicrobial therapy on bacterial vaginosis in non-pregnant women" (in en). Cochrane Database of Systematic Reviews (3): CD006055. doi:10.1002/14651858.CD006055.pub2. PMID 19588379. http://doi.wiley.com/10.1002/14651858.CD006055.pub2. 
  20. Kayode, F.; Folasade, O.; Frank, M. A.; Rene, S. H. (2010-05-05). "Antimicrobial susceptibility and serovars of salmonella from chickens and humans in ibadan, nigeria" (in en). Journal of Infection in Developing Countries. ISSN 1972-2680. https://ir.unilag.edu.ng/handle/123456789/7015. 
  21. Shittu, Adebayo; Oyedara, Omotayo; Abegunrin, Fadekemi; Okon, Kenneth; Raji, Adeola; Taiwo, Samuel; Ogunsola, Folasade; Onyedibe, Kenneth et al. (2012-11-02). "Characterization of methicillin-susceptible and -resistant staphylococci in the clinical setting: a multicentre study in Nigeria" (in en). BMC Infectious Diseases 12 (1): 286. doi:10.1186/1471-2334-12-286. ISSN 1471-2334. PMC 3529121. PMID 23121720. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3529121. 
  22. Marais, Frederick; Minkler, Meredith; Gibson, Nancy; Mwau, Baraka; Mehtar, Shaheen; Ogunsola, Folasade; Banya, Sama S.; Corburn, Jason (2016-06-01). "A community-engaged infection prevention and control approach to Ebola" (in en). Health Promotion International 31 (2): 440–449. doi:10.1093/heapro/dav003. ISSN 0957-4824. PMID 25680362. https://academic.oup.com/heapro/article/31/2/440/1750493.