Jump to content

Hafsat Idris

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hafsat Idris
Ọjọ́ìbíHafsat Ahmad Idris
14 Oṣù Keje 1987 (1987-07-14) (ọmọ ọdún 37)
Shagamu, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actress, Film Maker
Ìgbà iṣẹ́2015–present
Notable credit(s)Best known for her appearance in Barauniya
Àwọn ọmọ2

Hafsat Ahmad Idris tí a tún mọ̀ sí Hafsat Idris (táa bí ní 14 Oṣù Keèje, Ọdún 1987),[1][2] jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó maá n ṣiṣẹ́ lágbo òṣèré ti Kannywood. Eré àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó ti kópa ni fíìmù Barauniya (2016).[3] Ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jùlọ ní ọdún 2019.[4]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Hafsat jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínẹ̀ Kánò, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n ìlú ṢàgámùÌpínẹ̀ KánòÌpínẹ̀ Ògùn ni wọ́n bi sí, níbẹ̀ náà ló sì dàgbà sí.[5][6] Ó ṣe àkọ́kọ́ ìfihàn rẹ̀ ní agbo òṣèré Kannywood nínu fíìmù táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Barauniya pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Ali Nuhu, àti Jamila Nagudu.[7][8]

Ní ọdún 2018, ó dá ilé-iṣẹ́ agbéréjáde sílẹ̀ tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ramlat Investment. Ilé-iṣẹ́ náà ti gbé àwọn eré bi mélòó kan jáde ní ọdún 2019 tí ó fi mọ́ fíìmù Kawaye, èyítí òun àti àwọn òṣèré míràn bíi Ali Nuhu àti Sani Musa Danja dì jọ kópa nínu rẹ̀.[9]

Àwọn ìyẹ́sí tí ó ti gbà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Ẹ̀ye Ẹ̀ka Èsì
2017 City People Entertainment Awards Most Promising Actress[10] Wọ́n pèé
2018 City People Entertainment Awards Best Actress [11] Gbàá
2019 City People Entertainment Awards Best Actress Gbàá
2019 City People Entertainment Awards Face of Kannywood Gbàá

Àkójọ àwọn eré tí ó ti kópa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Hafsat ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tó fi mọ́ àwọn wọ̀n yìí:[12]

Àkọ́lé Ọdún
Biki Buduri ND
Furuci ND
Labarina ND
Barauniya 2015
Makaryaci 2015
Abdallah 2016
Ta Faru Ta Kare 2016
Rumana 2016
Da Ban Ganshi Ba 2016
Dan Almajiri 2016
Haske Biyu 2016
Maimunatu 2016
Mace Mai Hannun Maza 2016
Wazir 2016
Gimbiya Sailuba 2016
Matar Mamman 2016
Risala 2016
Igiyar Zato 2016
Wata Ruga 2017
Rariya 2017
Wacece Sarauniya 2017
Zan Rayu Da Ke 2017
Namijin Kishi 2017
Rigar Aro 2017
Yar Fim 2017
Dan Kurma 2017
Kawayen Amarya 2017
Dokita Surayya 2018
Algibla 2018
Ana Dara Ga Dare Yayi 2018
Mata Da Miji 2019

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Hafsa Idris [HausaFilms.TV - Kannywood, Fina-finai, Hausa Movies, TV and Celebrities]". hausafilms.tv. Retrieved 22 May 2019. 
  2. Lere, Muhammad (17 December 2016). "Getting married is my priority – Kannywood actress, Hafsat Idris - Premium Times Nigeria". Premium Times. Retrieved 22 May 2019. 
  3. Ismail, Kamardeen; Ikani, John; Dauda, Aisha (13 July 2018). "6 hot Kannywood actresses who are still single". Daily Trust. Archived from the original on 15 July 2020. Retrieved 15 July 2020. 
  4. "Kannywood Winners Emerge @ 2019 City People Movie Awards". City People Magazine. City People Magazine. 14 October 2019. Retrieved 15 July 2020. 
  5. "Hafsa Idris Biography - Age". MyBioHub. 2 June 2017. Retrieved 15 July 2020. 
  6. Adamu, Muhammed (30 January 2017). "Hafsat Ahmad Idris: Epitome of hardwork, resilient actress". Blueprint. Retrieved 22 May 2019. 
  7. "Ba zan iya fitowa karuwa a fim ba - Inji Hafsat Barauniya". Gidan Technology Da Media (in Èdè Árábìkì). Archived from the original on 2020-11-16. Retrieved 2020-09-24. 
  8. Nwafor; Nwafor. "10 Kannywood beauties rocking the movie screens - Events Chronicles". https://eventschronicles.com/ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-07-15. Retrieved 2020-09-24.  External link in |website= (help)
  9. Muhammed, Isiyaku (24 September 2019). "Hafsat Idris hits one million followers on Instagram". Daily Trust. Retrieved 15 October 2019. 
  10. People, City (11 September 2017). "2017 City People Movie Awards (Nominees For Kannywood)". City People Magazine. Retrieved 22 May 2019. 
  11. People, City (24 September 2018). "Winners Emerge @ 2018 City People Movie Awards". City People Magazine. Retrieved 15 October 2019. 
  12. "Hafsa Idris Biography | Age | Wikipedia | Pictures". 360dopes. 30 August 2018. Retrieved 22 May 2019. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]