Half of a Yellow Sun
Ìrísí
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa ìwé náà. Fún fún àtúnṣe fíìmù, ẹ wo: Half of a Yellow Sun (film).
Olùkọ̀wé | Chimamanda Ngozi Adichie |
---|---|
Country | UK |
Language | English |
Genre | Historical fiction |
Set in | Nigeria |
Publisher | 4th Estate |
Publication date | 2006 |
Media type | Print (Hardback) |
Pages | 448 pp |
ISBN | Àdàkọ:ISBNT |
OCLC | 78988623 |
Half of a Yellow Sun jẹ́ àròkọ tí òǹkọ̀wé ọmọ Nàìjíríà, Chimamanda Ngozi Adichie kọ. Ó tẹ̀ẹ́ jáde ní ọdún 2006 nípasẹ̀ 4th Estate. Àròkọ náà, tí wọ́n fi Nàìjíríà ṣe ibùdó ìtàn, sọ ìtàn Ogun Biafra nípasẹ̀ ojú-inú àwọn òṣèré Olanna, Ugwu, àti Richard.[1]
Ìhun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọsílẹ̀ náà wáyé ní Nàìjíríà ṣáájú àti lásìkò Ogun Abẹ́lé Nàìjíríà (1967 sí 1970). Ipa ogun ni a fi hàn nípasẹ̀ àwọn ìbáṣepọ̀ àwọn ìgbésí ayé ènìyàn márùnún pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin ìbejì ti oníṣòwò kan tí ó ní ipa, ọ̀jọ̀gbọ́n kan, ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì kan, àti ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà kan. Lẹ́yìn tí Biafra kéde ìyàsọ́tọ̀, ìgbésí ayé àwọn ẹ̀dá-ìtà pàtàkì yí padà pátápátá, tí ìwà ìkà ogun abẹ́lé àti àwọn ìpinnu tí wọ́n ṣe nínú ìgbésí ayé ara wọn sì tú wọn ká.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Nixon, Rob (1 October 2006). "A Biafran Story". The New York Times. https://www.nytimes.com/2006/10/01/books/review/Nixon.t.html.