Jump to content

Ogun Abele Nigeria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ogun Biafra)
Ogun Abélé ilẹ̀ Nàìjíríà
Part of Cold War àti decolonisation of Africa
Soldiers in the Nigerian Civil War.jpg
Marching soldiers of the Biafran Armed Forces[1]
Ìgbà 6 July 1967 – 15 January 1970
(2 years, 6 months, 1 week and 2 days)
Ibùdó Southeastern Nigeria
Àbọ̀ Nigerian victoryÀdàkọ:Bulleted list
Torí ilẹ̀
changes
Biafra rejoins Nigeria
Àwọn agbógun tira wọn
Àwọn apàṣẹ

Foreign mercenaries:
Agbára
Nigerian Armed Forces:
Àdàkọ:Country data Biafra Biafran Armed Forces:
Òfò àti ìfarapa
Combatants killed: 45,000[32]–100,000[35][36]
Biafran civilians died from famine during the Nigerian naval blockade[37]

Displaced: 2,000,000–4,500,000[38]


Refugees: 500,000[39]–3,000,000[citation needed]



Ogún Abẹ́lé ilẹ̀ Nàìjíríà wáyé láàárín ọjọ́ Kẹfà Oṣù Okúdù Ọdún 1967 sí ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Ṣẹ́ẹ́rẹ́: tí a tún mọ̀ sí (Ogun Nàìjíríà - Biafra tàbí Ogun Biafra) jẹ́ Ogun Abẹ́lé tí ó wáyé láàárín ìjọba Nàìjíríà àti orílè-èdè Biafra, ìpínlẹ̀ tí ó fé dádúró tì ó ti fẹ́ gba òmìnira kúrò lára Nàìjíríà ní ọdún 1967. Ọgágun Yakubu Gowon ni ó ń darí Orílẹ̀èdè Nàìjíríà Lt. Colonel Odumegwu Ojukwu sí ń darí Biafra. Èròngbà àwọn olùfẹ́ ẹ̀yà Ìgbò tí wọ́n rò pé àwọn kò lè bá ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe pọ̀ mọ torí pé àwọn Mùsùlùmí ẹ̀yà  Haúsá-Fúlàní tí àríwá Orílẹ̀èdè Nàìjíríà tí jẹ gàba ní Biafra. Ìyọrísí ìkọlù yìí láti rògbòdìyàn  ìṣèlú, ọrọ̀ ajé, ẹ̀yà, ajẹmáṣà àti ẹ̀sìn ló bí pínpín Nàìjíríà láti ọdún 1960  sí 1963. Lára àwọn aṣokùnfà ogun ní ọdún 1966 ni ìjà ẹ̀sìn àti ìṣègbè ẹ̀yà Ìgbò ní Apá Àríwá Nàìjíríà. Ìdìtẹ̀gbàjọba, àti ìrẹ́jẹ àwọn Ìgbò ní apá àríwá Naijiria. Bákan náà Ìjẹ gàba lórí ìgbéjáde epo rọ̀bì tó lérè gọbọi lórí ní apa Niger Delta náà kópa ribiribi nínú ogun abẹ́lé náà. Láàárín ọdún kan, àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti yí gbogbo kọ̀rọ̀-kọ́ndú ilẹ̀ Ìgbò Biafara po tí ó fi mọ́ orísun epo tí ó wà ní ìlú Port Harcourt.[citation needed]. Wọ́n mọ odi yí wọn ká tínwọn kò sì gbà kí ẹnikẹ́ni nínú ẹ̀yà Ìgbò ó jáde síta, èyí f a ebi ọ̀pàgbà f'ọwọ́-mẹ́kẹ́ fún tẹ́rú tọmọ wọn.[40] Láàárín ọdún méjì ati abọ̀ tí ogun náà fi wáyé, iye àwọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ ẹ̀yà Ìgbò tí wọ́ ṣ'aláìsí láti ọwọ́ àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ ọgọ́rún kan, nígbà tí iye àwọn tí wọ́n ṣ'aláìsí látàrí ebi òpàpàpàlà jẹ́ mílíọ́nù lọ́nà ọgọ́rùn-un márùn-ún ènìyàn.[41]

Nígbà tí yóò fi di àárín ọdún 1968, àwọn oníròyìn bẹ̀rẹ̀ sí ń fi àwòrán àwọn àgbà àti ọmọdé tí ebi ti sọ di aláabọ̀ ara nínú àwọn ẹ̀yà ìgbò léde nínú àwọn ìwé ìròyìn tí wọ́n ń jáde ní àwọn orílẹ̀-èdè òkèrè[citation needed]. Àwòrán àwọn tí ebi ń pa wọ̀nyí beeẹ̀ sí ń mú kí àwọn ará ilẹ̀ òkèèrè ó beeẹ̀ sí ń fi oju àánú wo àwọn ènìyàn wọ̀nyí, tí ó sì mú kí àwọn àjọ 3lẹ́yinjú àánú tí kìí ṣe ti ìjọba ó ma dá owó , ounje , aṣọ àti àwọn ohun ìgbáyé-gbádùn mìíràn ránṣẹ́ sí wọn. Orílẹ̀-èdè United Kingdom àti Soviet Union ni wọ́n fẹ̀yìn pọn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti bori Biafra nígbà náà, nígbà tí orílẹ̀-èdè France àti Isreal ṣagbátẹrù fún àwọn Biafra láti kojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà padà. Àmọ́ àwọn Amẹ́ríkà ní ti wọn kò ṣ'ègbè lẹ́yìn ẹnìkọkan, wọ́n kò fara mọ́ ìfìyà-jẹni tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń fi jẹ àwọn Igbo yí, bákan náà ni wọ́n bu ẹnu atẹ́ lu ìgbàẹ́sẹ̀ ìyapa àwọn Biafra kúrò lára orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[42] [43][44]


Ohun ti bo fa ogun yí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹlẹ́yà-m'ẹ̀yà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ohun àkókọ́ tí ó fa ogun yí ni ó níṣe pẹ̀lú ìdàpọ̀ gbogbo ẹ̀yà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lásìkò ìṣèjọba àmúnisìn ní ọdún 1914, èyí ni dídá Northern protectorate, Lagos Colony àti Southern Nigeria protectorate tí a tún mọ̀ sí Eastern Nigeria) papọ̀ láti lè jẹ́ kí ìṣèjọba orílẹ̀-èdè náà ó f'ẹsẹ̀ múlẹ̀ nítorí gbígòòrò tí àwọn agbègbè orílẹ̀-èdè tí a ti mẹ́nu bá lókè yí gbòòrò tí oríṣiríṣi ẹ̀yà sì wà ní ibẹ.[45] Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìdàpọ̀ yí kò fiyè sí ìyàtọ̀ tí ó wà láàárín ẹ̀yà, èdè ati ẹ̀sìn tí ó wà láàárín àwọn ènìyàn ilé Nàìjíríà lásìkò náà, èyí ni ó mú ìbérù ati ìfòyà ó gbilẹ̀ nínú wọn tí ó sì mú kí kálukú àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí ó ma jìjàgùdù lórí ìṣèlú ara-ẹni àti ìmójútó okòwò ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan. Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gb'òmìnira lọ́wọ́ ìjọba àmúnisìn ilẹ̀ Britain ní ọjọ́ kìíní oṣù Kẹwàá ọdún 1960, nígbà tí gbogbo àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbé ibẹ̀ náà jẹ́ mílíọ́nù márùndínláàdọ́ta ó dín diẹ̀, nígbà tí iye ẹ̀yà tí ó wà níbẹ̀ jẹ́ ọgbàọ́rùn ún mẹ́ta[46]. Nígbà tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gba òmìnira, àwọn agbègbè tí wọ́n tóbi jùlọ ni àsìkò náà ni apá ìlà Oòrùn tí àwọn ẹ̀yà Igbò ea, lásìkò yí, wọ́n kó ìdá 60–70% nínú iye ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà;[47] Àwọn Hausa-Fulani lábẹ́ ìṣèjọba ilẹ̀ Sultanate of Sokoto, ni wọ́n kó ìdá 67% lápá òkè ọya, bákan náà ni àwọn Yorùná ní apá Ìwọ̀-Oòrùn orílẹ̀-èdè náà kò ìdá 75%;[48].[49] Lóòtọ́, àwọn ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan wọ̀nyí ni wọ́n ní ilẹ̀ tiwọn tí wọ́n sìntú fọ́nká sí orígun orílẹ̀-èdè náà Nígbà tí ogun náà bẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 1967, iye àwọn ọmọ ẹ̀yà Igbo tí wọ́n wà ní àwọn orígun ilẹ̀ Nàìjíríà kò sàn ní ẹgbẹ̀rún márùún pàá pàá jùlọ ní ìlú Èkó [50].

Àwọn itọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Nigeria’s Northern Elders Forum: Keeping the Igbo is Not Worth a Civil War". Council on Foreign Relations (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  2. "The Literary Magazine - the Biafra War and the Age of Pestilence by Herbert Ekwe Ekwe". Archived from the original on 2018-08-20. Retrieved 2011-01-04. 
  3. Shadows: Airlift and Airwar in Biafra and Nigeria 1967–1970, by Michael I. Draper (ISBN 1-902109-63-5)
  4. Baxter 2015.
  5. United States Department of State: The Office of Electronic Information, Bureau of Public Affairs (25 October 2005). "Nigerian Civil War". 2001-2009.state.gov. 
  6. "Israel, Nigeria and the Biafra Civil War, 1967–1970". 
  7. Nigeria Since Independence: The First Twenty-five Years : International Relations, 1980. Page 204
  8. Sadleman, Stephen (2000). The Ties That Divide. p. 86. ISBN 9780231122290. https://books.google.com/books?id=_8UzCgAAQBAJ&q=ethiopia+support&pg=PA87. Retrieved 8 June 2018. 
  9. Stearns, Jason K. Dancing in the Glory of Monsters: The Collapse of the Congo and the Great War of Africa (2011), p. 115.
  10. Wrong, Michela. In the Footsteps of Mr. Kurtz: Living on the Brink of Disaster in Mobutu's Congo (2000), p. 266.
  11. Biafra Revisited, 2006. p. 5.
  12. Spencer C. Tucker, The Roots and Consequences of Civil Wars and Revolutions: Conflicts that Changed World History, (ISBN 9781440842948)
  13. 13.0 13.1 13.2 13.3 13.4 "The Biafran War, Nigerian History, Nigerian Civil War". Archived from the original on 12 March 2008. 
  14. Diamond, Stanley (2007). "Who Killed Biafra?". Dialectical Anthropology 31 (1/3): 339–362. doi:10.1007/s10624-007-9014-9. JSTOR 29790795. 
  15. "Biafran Airlift: Israel's Secret Mission to Save Lives". Eitan Press. United With Israel. www.unitedwithisrael.org. 13 October 2013. Accessed 13 January 2017.
  16. Genocide and the Europeans, 2010, p. 71.
  17. 17.0 17.1 There's A Riot Going On: Revolutionaries, Rock Stars, and the Rise and Fall of '60s Counter-Culture, 2007. p. 213.Àdàkọ:Fcn
  18. The USSR in Third World Conflicts: Soviet Arms and Diplomacy in Local Wars 1945–1980, 1986, p. 91.Àdàkọ:Fcn
  19. 19.0 19.1 Hurst, Ryan (21 June 2009). "Republic of Biafra (1967–1970)". 
  20. Fellows, Lawerence (14 January 1970). "Nigerian Rejects Help From Groups That Aided Biafra". The New York Times. New York City. 
  21. Chukwuemeka, Kenneth (December 2014). "Counting the Cost: The Politics of Relief Operations in the Nigerian Civil War, A Critical Appraisal". African Study Monographs 35 (3&4): 138. https://repository.kulib.kyoto-u.ac.jp/dspace/bitstream/2433/193254/1/ASM_35_129.pdf. 
  22. Griffin, French Military Policy in the Nigerian Civil War (2015), p. 122. "Starting in October 1967, there were also direct Czech arms flights, by a network of pilots led by Jack Malloch, a Rhodesian in contact with Houphouët-Boigny and Mauricheau-Beupré."
  23. Malcolm MacDonald: Bringing an End to Empire, 1995, p. 416.
  24. Ethnic Politics in Kenya and Nigeria, 2001, p. 54.Àdàkọ:Fcn
  25. Africa 1960–1970: Chronicle and Analysis, 2009, p. 423.Àdàkọ:Fcn
  26. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named griffin
  27. 27.0 27.1 Nkwocha, 2010: 156
  28. 28.0 28.1 28.2 Karl DeRouen & U. K. Heo (2007). Civil wars of the world: Major conflicts since World War II. Tomo I. Santa Bárbara: ABC CLIO, p. 569. ISBN 978-1-85109-919-1.
  29. Alfred Obiora Uzokwe (2003). Surviving in Biafra: The Story of the Nigerian Civil War : Over Two Million Died. Lincoln: iUniverse, p. xvi. ISBN 978-0-595-26366-0.
  30. 30.0 30.1 Dr. Onyema Nkwocha (2010). The Republic of Biafra: Once Upon a Time in Nigeria: My Story of the Biafra-Nigerian Civil War – A Struggle for Survival (1967–1970). Bloomington: AuthorHouse, p. 25. ISBN 978-1-4520-6867-1.
  31. Biafran War. GlobalSecurity.org.
  32. 32.0 32.1 32.2 Phillips, Charles, & Alan Axelrod (2005). "Nigerian-Biafran War". Encyclopedia of Wars. Tomo II. New York: Facts On File, Inc., ISBN 978-0-8160-2853-5.
  33. West Africa. Londres: Afrimedia International, 1969, p. 1565. "Malnutrition affects adults less than children, half of whom have now died, reports Debrel, who also describes the reorganisation of the Biafran army after the 1968 defeats, making it a 'political' army of 110,000 men; its automatic weapons, ..."
  34. Stan Chu Ilo (2006). The Face of Africa: Looking Beyond the Shadows. Bloomington: AuthorHouse, p. 138. ISBN 978-1-4208-9705-0.
  35. Paul R. Bartrop (2012). A Biographical Encyclopedia of Contemporary Genocide. Santa Bárbara: ABC-CLIO, p. 107. ISBN 978-0-313-38679-4.
  36. Bridgette Kasuka (2012). Prominent African Leaders Since Independence. Bankole Kamara Taylor, p. 331. ISBN 978-1-4700-4358-2.
  37. Stevenson 2014, p. 314: "The mass killing during the Nigeria-Biafra War was the result of a 'deliberately imposed economic blockade on the inhabitants of Nigeria's southeastern region by the country's federal government' that led to an induced 'famine in which over two million people died of starvation and related diseases.'"
  38. Godfrey Mwakikagile (2001). Ethnic Politics in Kenya and Nigeria. Huntington: Nova Publishers, p. 176. ISBN 978-1-56072-967-9.
  39. DeRouen & Heo, 2007: 570
  40. Campbell, Colin (1987-03-29). "Starvation Was The Policy" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/1987/03/29/books/starvation-was-the-policy.html. 
  41. "ICE Case Studies: The Biafran War". American University: ICE Case Studies. American University. 1997. Archived from the original on 14 February 2017. Retrieved 6 November 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  42. Chinua, Achebe (2012). There was a country: a personal history of Biafra. pearson. 
  43. "Foreign Relations of the United States, 1964–1968,". Office of the Historian, US State Department. Retrieved 2022-04-25. 
  44. Àdàkọ:Cite thesis
  45. Times, Premium (2021-07-03). "The British, Nigeria and the 'Mistake of 1914', By Eric Teniola". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-10-05. 
  46. Oyeranmi, S (2012-07-12). "The Colonial Background to the Problem of Ethnicity in Nigeria: 1914-1960". Journal of History and Diplomatic Studies (African Journals Online (AJOL)) 8 (1). doi:10.4314/jhds.v8i1.2. ISSN 1597-3778. 
  47. "Igbo | people". Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-11. 
  48. Orji I., Ema. "Issues on ethnicity and governance in Nigeria: A universal human Right perspectives.". Fordham International Law Journal 25 (2 2001 Article 4). https://ir.lawnet.fordham.edu/cgi/viewcontent.cgi?article=1819&context=ilj. 
  49. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  50. Olawoyin, Historical Analysis of Nigeria–Biafra Conflict (1971), pp. 32–33. "The Ibo like the Hausa and Yoruba, are found in hundreds in all towns and cities throughout the Federation. Even at the period of the Civil War, they numbered more than 5,000 in Lagos alone."