Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Songhai Empire

c. 1340–1591
 

The Songhai Empire, (ca. 1500)
Capital Gao
Language(s) Songhai
Religion Islam
Government Monarchy
Sonni; later Askiya
 - 1468-1492 Sunni Ali (first)
 - 1588-1591 Askia Mohammad I (last)
History
 - Songhai state emerges at Gao c.1000
 - Songhai permanently free of Mali Empire c. 1340
 - Songhai begins military expansion 1460
 - Sunni dynasty overthrown 1493
 - Songhai empire destroyed by Saadi dynasty 1591
 - Songhai establish Dendi Kingdom 1592

The Dendi Kingdom ends 1901

Area
 - 1500[1] 1,400,000 km2 (540,543 sq mi)
 - 1550[2] 800,000 km2 (308,882 sq mi)
Currency Cowries
(gold, salt and copper were also common in the empire)
Warning: Value specified for "continent" does not comply

Ile Obaluaye Songhai, bakana bi Ile Obaluaye Songhay, je ile-ijoba Afrika ni iwoorun Afrika. Lati ibere orundun 15th titi de opin orundun 16th, Songhai ni o je ikan ninu awon ile obaluaye Afrika totobijulo ni itan aye. Oruko re wa lati oruko awon eya eniyan to siwaju nibe, eyun awon Songhai. Oluilu re wa ni ilu Gao, nibi ti ile-ijoba Songhai kekere kan ti wa lati orundun 11th. Ibujoko agbara re wa ni koro apa Odo Oya ni orile-ede Niger loni ati Burkina Faso.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Hunwick, page xlix
  2. Taagepera, page 497