Jump to content

Irú (oúnjẹ)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Irú Èdè Yorùbátàbú Dawadawa (Hausa) tàbí Eware (Edo) tàbí Sumbala (Bambara) tàbí Narghi (Fula) jẹ́ Irú tó ti fermentí wọ́n sì máa ń lò láti fi dáná.[1] Ó jọ ogiri àti douchi. Bẹ́ẹ̀ sì ni ó gbajúmọ̀ káàkiri apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Africa, pàápàá nínú àwọn oúnjẹ wọn. Wọ́n máa ń lò ó láti se àwọn ọbẹ̀ ìbílẹ̀ bí i egusi, ilá, ewédú àti ọ̀gbọ̀nọ̀.[2]

Fáìlì:IRU.JPG
Dry iru cakes

wọ́n máa ń bọ̀ ọ́, tí wọ́n á sì nù ún kí wọ́n tó gbe sí ẹ̀gbé kan kó ferment - tó bá ti ferment, ó máa ń ní òórùn kan tó máa ń rùn bọ̀ǹbọ̀nọ̀. Wọ́n lè fi iyọ̀ sí kó ba lè pẹ̀ nílè dáadáa.

Wọ́n máa ń dì í róbóróbó tàbí kí wọ́n tọ́jú rẹ̀ pamọ́ fún ìgbà díẹ̀ láti rí èsì gidi.

Àwọn Yorùbá ni oríṣi irú méjì:

Orúkọ àti ìyàtọ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn orúkọ mìíràn tí wọ́n ń pe irú ni agbègbè mìíràn:

  • Èdè Manding: sunbala, sumbala, sungala, sumara Sumbala (or in French transcription soumbala) is a loan from Manding.
  • Èdè Haúsá: dawadawa, daddawa
  • Èdè Pulaar/Pular: ojji
  • Èdè Yorùbá: iru
  • Èdè Serer, Saafi, Wolof: netetou
  • Èdè Krio: kainda
  • Èdè Susu: Kenda
  • Èdè Zarma: doso mari
  • Èdè Dagbanli: Kpalgu
  • Èdè Mooré: Colgo
  • Èdè Konkomba: tijun, tijon

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Dawadawa: The Magical Food Ingredient". LivingTheAncestralWay (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-10-23. 
  2. Petrikova, Ivica; Bhattacharjee, Ranjana; Fraser, Paul D. (Jan 2023). "The 'Nigerian Diet' and Its Evolution: Review of the Existing Literature and Household Survey Data". Foods 12 (3): 443. doi:10.3390/foods12030443. PMC 9914143. PMID 36765972. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=9914143. 
  3. Abaelu, Adela M.; Olukoya, Daniel K.; Okochi, Veronica I.; Akinrimisi, Ezekiel O. (1990). "Biochemical changes in fermented melon (egusi) seeds (Citrullis vulgaris)". Journal of Industrial Microbiology 6 (3): 211–214. doi:10.1007/BF01577698.