Jean-Jacques Dessalines

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Jean-Jacques Dessalines
Jacques I
Emperor Jacques I of Haiti
Orí-ìtẹ́22 September 1804 – 17 October 1806
Orí-oyè6 October 1804
OrúkọJean-Jacques Dessalines
AṣájúEmpire Founded
Arọ́pọ̀Empire Abolished
Henri Christophe (as President of North Haiti)
Alexandre Pétion (as President of South Haiti)
AyabaMarie-Claire Heureuse Félicité
Jean-Jacques Dessalines
Governor-General of Haiti
In office
1 January 1804 – 22 September 1804
AsíwájúNone
Arọ́pòNone (position abolished) (succeeded himself as Emperor)

Jean-Jacques Dessalines (Àdàkọ:Lang-ht) (20 September 1758 – 17 October 1806) jẹ́ olórí Ijidide ara Haiti àti olórí àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè alomonira Haiti lábẹ́ àdéhùn ijigbepo 1801. Ó di adápàṣẹ nínú ìjọba rẹ̀, Ó sì sọ ara rẹ̀ di Ọbalúayé ilẹ̀ Haïti ni 1805.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Independent Haiti". Retrieved 27 November 2006.