René Préval
Ìrísí
René Préval | |
---|---|
President of Haiti | |
In office 14 May 2006 – 14 May 2011 | |
Alákóso Àgbà | Gérard Latortue Jacques-Édouard Alexis Michèle Pierre-Louis Jean-Max Bellerive |
Asíwájú | Boniface Alexandre |
Arọ́pò | Michel Martelly |
In office 7 February 1996 – 7 February 2001 | |
Alákóso Àgbà | Claudette Werleigh Rosny Smarth Jacques-Édouard Alexis |
Asíwájú | Jean-Bertrand Aristide |
Arọ́pò | Jean-Bertrand Aristide |
Prime Minister of Haiti | |
In office 13 February 1991 – 11 October 1991 | |
Ààrẹ | Jean-Bertrand Aristide |
Asíwájú | Martial Célestin |
Arọ́pò | Jean-Jacques Honorat |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kínní 1943 Cap-Haïtien, Haiti |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Lespwa |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Geri Benoit (Divorced) Solange Lafontant (Divorced) Elisabeth Delatour (2009–present) |
Alma mater | College of Gembloux Catholic University of Leuven University of Pisa |
Profession | Agronomist |
René Garcia Préval (ìpè Faransé: [ʁəne pʁeval]; born January 17, 1943) je oloselu ara orile-ede Haiti to je Aare orile-ede Haiti lati May 2006 de 14 May, 2011. Teletele, o tun ti je Aare lati February 7, 1996, titi di February 7, 2001, ati gege bi Alakoso Agba lati February 1991 titi di October 11, 1991.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |