Jump to content

Monpoint Jeune

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Monpoint Jeune
Aṣojú Ààrẹ Haiti
In office
Ọjọ́ kẹtàlèlógún Oṣù Kẹjọ, ọdún 1889 – Ọjọ́ kẹtàdínógún Oṣù Kẹ̀wá, ọdún 1889
AsíwájúFrançois Denys Légitime
Arọ́pòFlorvil Hyppolite

Borno Monpoint, tí wọ́n tún mọ̀ sí Monpoint Jeune, jẹ gẹ́gẹ́ bí i ààrẹ Haiti láti ọjọ́ kẹtàlèlógún Oṣù Kẹjọ sì ọjọ́ kẹtàlèlógún Oṣù Kẹ̀wá ọdún 1889.[1]

Gẹ́gẹ́ bí i gẹ́nẹ́rà, ó fi òpin sí ìlòdì tó tako ìjọba ààrẹ Pierre Théoma Boisrond-Canal ní Oṣù Kẹta ọdún 1878.

Lẹ́yìn ìjọba Ààrẹ François Denys Légitime, ó di yíyàn gẹ́gẹ́ bí i ààrẹ ìjọba aṣojú àti ààrẹ tó kàn fún orílẹ̀-èdè Haiti ní ọjọ́ kẹtàlèlógún Oṣù Kẹjọ, ọdún 1889.

Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù Kẹ̀wá, ọdún 1889, mínísítà fún ètò-ọ̀gbìn, Florvil Hyppolite rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ààrẹ.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Vilsaint, Fequiere; Hall, Michael R. (2021). Historical Dictionary of Haiti. p. 339. ISBN 9781538127537. https://books.google.com/books?id=yG4yEAAAQBAJ&pg=PA339&dq=%22Monpoint+Jeune%22+-wikipedia&hl=en&newbks=1&newbks_redir=0&source=. Retrieved October 6, 2025.