Kehinde Olorunyomi
Kehinde Olorunyomi ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kíní ọdún 1981. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, ònkọ̀tàn, àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eré ṣiṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kẹ́hìndé bẹ̀rẹ̀ eré tíátà ní orí eré ọlọ́sọ̀sẹ̀ ti Everyday People ọdún 2001, [1] She is remembered for her role in the defunct soap opera Domino,[2] níbi tí ó ti ń kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtan "Stella Lord-Williams", ti ó jẹ́ aya fún olú-èdá ìtàn "Oscar" nínú eré náà.
Ó dara pọ̀ mọ́ eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ Tinsel ní ọdún 2017, níbi tí ó ti kópq gẹ́gẹ́ ẹ̀dá ìtàn "Tọ̀míwá Àjàyí"[3] Kẹ́hìndé ti.kópa nínú eré orísiríṣi bíi: The Novelist, [1] Couple's Award,[2]Divorce not allowed,[3] Archived 2021-07-28 at the Wayback Machine. Bachelor's Eve [4] bloodlines season 1,[5] àti Forever Within Us, [6]
Ìṣọwọ́ kọ ìtàn rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọlọ́runyọmí bẹ̀rẹ̀ kíkọ ìtàn ati eré rẹ̀ ní ọdún 2006 nígbà tí ó kọ ìtan aládùn tí wọ́n fi gbé eré Mamush jáde. Ó ti kọ eré tí uó ti lé ní àádọ́ta tí wọ́n ti gbé jáde ní sinimá ati eré àtìgbà-dégbà ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ lórí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán. Ó ti ìtàn fún àwọn ilé-iṣẹ́ tí wọ́ń gbé eré jáde bí M-Net Africa’s AMOF (Africa Magic Original Films), ati fún àwọn gbajú-gbajà òṣèré bíi: Desmond Elliot, Uche Jombo, Ayo Adesanya, Bimbo Akintola, Charles Okafor, Ego Boyo, Ramsey Noah, àti Mike Ezuruonye.
Ọlọ́runyọmí ni aláṣẹ àti olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Nextlevel Cinema, tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tí ó ń gbére jáde láti ọdún 2012. Ilé-iṣẹ́ yí ti gbé eré márùn ún tí ó lààmì-laaka jáde, àwọn ni The Perfect Plan (2012),[4] Forever Within Us (2014),[5] One Moment in Time (2014),[6] The Novelist (2015),[7] Tesho (2016). Eré The Novelist ni ó kálé káko ní ilé-ìwòran sinimá ati orí ẹ̀rọ ayélujára ní ọdún 2016.[8] Couple's Award [9]
Ọlọ́runyọmí gba amì-ẹ̀yẹ Ghana Movie Awards (GMA) ní ọdún 2012 fún eré In the Cupboard tí Desmond Elliot gbé jáde. Lára awọn eré mìíràn tí Kẹ́hìndé tún kọ ni Husbands of Lagos Season 1 (2014) fún Irokotv, Missing Steps (2016) tí ó kọ nípa ìjọba orílẹ̀-èdè Switzerland ati Nigerian tí Charles Okafor gbé jáde[10] Òun ló tún kọ Oge’s Sister tí Uche Jombo gbé jáde. [11] Òun ló kọ Ojú Ànú tí Ayo Adesanya gbé jáde, bákan náà The Patient tí ilé-iṣẹ́ M-Net Africa gbé jáde.[12]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí adarí eré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eré Couple's Award[13] ni ó sọ Kẹ́hìndé di lààmì-laaka nídí iṣẹ́ dídarí eré, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé òun ló kọ eré náà ti ó sì tún kkópa nínú rẹ̀. [14][15]
Ìgbé ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọlọ́runyọmí ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ Adéwùmí Odùkọ̀yà[16] ẹni tí ó jẹ́ amojú ẹ̀rọ fún ilé ìwòran Nextlevel Cinema . Wọ́n bímọ́ ọkùnrin kan lẹ́yìn ìgbéyàwó wọn ní ọdún 2013. [17]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Izuzu, Chidumga. "#ThrowbackThursday: Do you remember hit TV series "Everyday Pe ople?"". Archived from the original on 2017-08-03. Retrieved 2020-11-08.
- ↑ Olamide Jasanya (April 10, 2013). "Actress Kehinde Olorunyomi delivers first child in the US". thenet.ng. Nigerian Entertainment Today. Retrieved May 28, 2017.
- ↑ Haliwud (2015-10-10). "Nollywood Star, Kehinde Olorunyomi Flaunt Dollar Bills On Instagram". Information Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28.
- ↑ "Trailer: Watch Joseph Benjamin, Kehinde Olorunyomi and Ini Edo make 'The Perfect Plan'". Thenet.ng. 2014-05-03. Retrieved 2017-05-30.
- ↑ Chidumga Izuzu (April 29, 2015). "Forever Within Us—Watch Blossom Chukwujekwu, Bayray Mcnwizu, Seun Akindele in trailer". pulse.bg. Pulse NG. Archived from the original on July 7, 2017. Retrieved May 28, 2017.
- ↑ Adunni Amodeni. "Movie Review: One Moment In Time ▷ NAIJ.COM". Entertainment.naij.com. NG. Retrieved 2017-05-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "The Novelist Nollywood Movie: Rykardo Agbor, Ifeanyi Kalu Star In Kehinde Olorunyomi's Latest Film" (in en-US). NaijaGistsBlog Nigeria, Nollywood, Celebrity ,News, Entertainment, Gist, Gossip, Inspiration, Africa. 2016-04-18. https://naijagists.com/the-novelist-nollywood-movie-rykardo-agbor-ifeanyi-kalu-star-in-kehinde-olorunyomis-latest-film/.
- ↑ "The Novelist Archives - Online Entertainment and Lifestyle Magazine in Nigeria". Happenings.com.ng. 2016-05-17. Archived from the original on 2017-12-28. Retrieved 2017-05-30.
- ↑ "Find Out Why Kehinde Olorunyomi Is Excited About Her Latest Movie ‘Couple’s Award’" (in en-US). Trybe Movie Channel. 2017-11-21. Archived from the original on 2017-12-28. https://web.archive.org/web/20171228054122/http://trybes.tv/news/find-out-why-kehinde-olorunyomi-is-excited-about-her-latest-movie-couples-award/.
- ↑ "‘It’s no paradise’: Switzerland funds Nigerian TV series to discourage migrants from coming".
- ↑ "Oge's Sister Archives". BellaNaija.com. 2017-05-07. Retrieved 2017-05-30.
- ↑ "RITA DOMINIC, FUNKE AKINDELE, DESMOND ELLIOT WIN AMSTEL MALTA'S AMVCA" (in en-US). BlackHouse Media (BHM). 2014-03-10. https://bhmng.com/rita-dominic-funke-akindele-desmond-elliot-win-big-amstel-maltas-amvca/amp/.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Find Out Why Kehinde Olorunyomi Is Excited About Her Latest Movie ‘Couple’s Award’" (in en-US). Trybe Movie Channel. 2017-11-21. Archived from the original on 2017-12-28. https://web.archive.org/web/20171228054122/http://trybes.tv/news/find-out-why-kehinde-olorunyomi-is-excited-about-her-latest-movie-couples-award/.
- ↑ "#YNaija2017Review: Isoken, Potato Potahto, Hakkunde… See the 10 best films of 2017 » YNaija" (in en-GB). YNaija. 2017-12-21. https://ynaija.com/ynaija2017review-isoken-potato-potahto-hakkunde-see-the-10-best-films-of-2017/.
- ↑ "Couple Awards: Kehinde Olorunyomi’s New Film Hits Cinema November 10, To Release Trailer October 10" (in en-US). Nigerian Women Diary. 2017-10-03. http://www.nigerianwomendiary.com/2017/10/couple-awards-kehinde-olorunyomis-new-film-hits-cinema-november-10-to-release-trailer-october-10-2/.
- ↑ "Why I said my husband can’t cheat on me —Kehinde Olorunyomi" (in en-US). Punch Newspapers. http://punchng.com/why-i-said-my-husband-cant-cheat-on-me-kehinde-olorunyomi/.
- ↑ "Actress Kehinde Olorunyomi delivers first child in the US". Thenet.ng. 2013-04-10. Retrieved 2017-05-30.
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from October 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Webarchive template wayback links
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1981
- Nigerian actresses
- 21st-century Nigerian actresses
- Nigerian screenwriters