Jump to content

Lilian Afegbai

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lilian Afegbai
Lilian Afegbai at a photoshoot
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kọkànlá 1991 (1991-11-11) (ọmọ ọdún 33)
Edo State, Edo State, Nigeria
Iṣẹ́Actress, producer
Ìgbà iṣẹ́2013—present

Lilian Afegbai (tí wọ́n bí ní 11 November 1991) jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, àti aṣàgbéjáde fíìmù agbéléwò. Ó fìgbà kan jẹ́ akópa nínú ètò Big Brother Africa.[1] Ní ọdún 2018, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA)[2] fún fíìmù ìbílẹ̀ tó dára jù ní ọdún 2018.[3] Ní ọdún 2019, ó ṣe ìdásílẹ̀ ìdókòwò rẹ̀, èyí tó jẹ́ títa aṣọ fún eré-ìdárayá àti aṣọ-àwọ̀tẹ́lẹ̀, tó pè ní "Lilly’s Secret" [4][5]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Afegbai ní 11 November 1991. Ipinle Edo, ní Nàìjíríà ni ó dàgbà sí.

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lilian Afegbai kópa nínú ìdíje Big Brother Africa, ní ọdún 2014, ó sì tipa ètò yìí di gbajúmọ̀.[6] Ó kópa nínú fíìmù ti ọdún 2015, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Road to yesterday.[7] Ó sì tún farahàn nínú fíìmù kékeré kan tí àkọ́lé rè ń jẹ́ Pepper soup.[8] Ó farahàn nínú fíìmù ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ ti Mnet, ìyẹn Do good.[9] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn aṣagbátẹrù fíìmù Dark Past.[10] Ó ṣèdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ EEP entertainment.[11] Bound ni àkọ́lé fíìmù kejì tó ṣàgbéjáde, àwọn òṣèré bí i Rita Dominic, Enyinna Nwigwe, Joyce Kalu àti Prince Nwafor ló wà nínú eré náà.[12]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Fíìmù Ojúṣe
2008 Tinsel Actor
2012 The Kingdom Actor
2015 Undercover Lover Actor
2015 Road to Yesterday Actor
2016 Pepper Soup Actor
2016 The Wedding Actor
2016 A Little White Lie Actor
2016 Happy Ending]] Actor
2016 The Therapist Actor
2017 Atlas Actor
2017 My Wife & I Actor
2017 The Women Actor
2017 Dance to My Beat Actor
2017 Dark Past Actor
2018 Dr Duncan Actor
2018 Grapes Actor
2018 Unmasked Actor
2018 The Spell Actor
2018 Moms at War Actor
2018 Merry Men: The Real Yoruba Demons Actor
2018 Ajoche Actor
2018 Bound Producer/Actor[13]
2020 True Vision Actor
2020 A Tiny Line Actor
2020 Fate of Alakada Actor
2020 Assistant Madams Actor
2021 Trump Card Actor
2021 The Reckoner Actor
2021 Third Avenue (film) Actor
2022 Double Strings Producer/Actor[14]
Ọdún Ayẹyẹ Ẹ̀bùn Olùgbà Èsì
2017 City People Entertainment Awards Most Promising Actress Self Gbàá [16]
2018 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Indigenous Movie Of the Year Bound Movie/Self Gbàá [17]
2021 African Choice Awards Actress of the Year Self Gbàá

[18]

2021 LA Mode Awards Celebrity Entrepreneur of the Year Self Gbàá

[19]

2018 LA Mode Awards Most Fashionable Female Celebrity of the year Self Gbàá

[20]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Chidumga (11 November 2016). "Lilian Afegbai: 3 thingsHotshot". Archived from the original on 15 November 2018. Retrieved 23 January 2024. 
  2. "African Magic Viewers Choice 2018 Award Winners List...". www.stelladimokokorkus.com. 
  3. "AMVCA 2018: Full list of winners". 2 September 2018. 
  4. "Nollywood producer Lilian Afegbai launches sensual lingerie line called Lilly's Secret". 29 January 2019. 
  5. "I get cold feet about marriage sometimes –Lilian Afegbai". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-16. Retrieved 2022-08-02. 
  6. "Nigerian housemate Lilian Afegbai evicted from Big Brother Hotshot 2014 - Daily Post Nigeria". 20 October 2014. 
  7. "Some people think I'm just beautiful without brain –Lilian Afegbai". April 2018. 
  8. Izuzu, Chidumga (7 April 2016). ""Pepper Soup": Watch Denrele Edun, Beverly Osu, Lisa Omorodion in teaser". [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. "New African Magic Comedy Series Premiere - Do Good". 8 July 2015. Archived from the original on 12 October 2020. Retrieved 23 January 2024. 
  10. "Dark Past - Latest Premium Movie Drama 2017 - Chika Ike- Mofe Duncan- Mercy Aigbe - Lilian Afegbai - Naijapals". www.naijapals.com. 
  11. "Lilian Afegbai makes production debut with 'Bound' - Nigeria Showbizz news - NewsLocker". Newslocker. 
  12. "Rita Dominic, Eyinna Nwigwe, Joyce Kalu & more star in Lilian Afegbai's Movie Debut as a Producer - See BTS Photos of "Bounds" - BellaNaija". www.bellanaija.com. 10 February 2017. 
  13. "Lilian Afegbai makes production debut with 'Bound'". 11 March 2018. 
  14. "Behind an Unsolved Murder lies a Dark Secret – Watch the Trailer for Lillian Afegbai's "Double Strings"". 21 February 2020. 
  15. "Lilian Afegbai". IMDb. 
  16. "List Of Winners At The 2017 City People Movie Awards". 9 October 2017. 
  17. "Complete List of Winners for the 2018 AMVCA". September 2018. Archived from the original on 2020-10-13. Retrieved 2024-01-23. 
  18. "Stars shone, winners emerge at Africa Choice Awards 2021". 15 December 2021. 
  19. "Green October Event 2021: The full list of winners | Lamodespot". 5 October 2021. Archived from the original on 27 June 2022. Retrieved 23 January 2024. 
  20. "Female Winners Lamode Magazine 2018 Green October Event | FabWoman". 2 October 2018.