Mọsún Fìlání

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mosún Fìlání Odùoyè
ÌbíÌbàdàn, ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Iṣẹ́actress
Awọn ọdún àgbéṣeLáti ọdún 2005 títí di àsìkò yìí
(Àwọn) ìyàwóKayode Oduoye
Àwọn ọmọ2

Mọsún Fìlání jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ olóòtú ètò orí rédíò ọmọ bíbí ìlú Ìbàdànìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ìgbà-èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí ní ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ṣùgbọ́n Ìpínlẹ̀ Èkìtì ni àwọn òbí rẹ̀ tí ṣẹ̀ wá. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí. [1] Mọsún lọ sí ilé ìwé gíga ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa olùkọ́, Abeokuta College of Education, bẹ́ẹ̀ náà ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ètò okoòwò ṣíṣe ní ifáfitì Tai Solarin University of Education.[2]

Iṣẹ́ tíátà rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Mọsún tí kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò, pàápàá jùlọ lédè Yorùbá. Bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ olóòtú lórí ètò lórí rédíò láti ọdún 2005. Wọ́n sìn tí yàn án fún àmì ẹ̀yẹ fún òṣèrébìnrin tí ó dára jù ní ipò amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ olú-ẹ̀dá ìtàn lọ́dún 2009 àti 2011.[3][4][5][6][7][8][9]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "My life as an actress, politician’s wife —Mosun Filani". Nigerian Tribune. July 12, 2015. Archived from the original on October 18, 2020. https://web.archive.org/web/20201018012439/https://www.tribuneonlineng.com/my-life-actress-politician%E2%80%99s-wife-%E2%80%94mosun-filani. Retrieved February 5, 2016. 
  2. ADERONKE ADEYERI (April 11, 2015). "I smile a lot but not to entice the opposite sex". The Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2015/04/i-smile-a-lot-but-not-to-entice-the-opposite-sex/. Retrieved February 5, 2016. 
  3. "Why I took a marital leave from acting". Encomium. Retrieved February 5, 2016. 
  4. "Nollywood Actress Mosun Filani returns with different strokes". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2015/07/photos-nollywood-actress-mosun-filani-returns-with-different-strokes/. Retrieved February 5, 2016. 
  5. "Mosun Filani stars in new radio dramla series". Nigerian Entertainment Today. Retrieved February 5, 2016. 
  6. Sola Bodunrin. "Mosun Filani Debunks Marriage Break-Up". Naij. Retrieved February 5, 2016. 
  7. "Mosun Filani and husband welcome second child". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2014/05/mosun-filani-and-husband-welcome-second-child/. Retrieved February 5, 2016. 
  8. Aderonke Ogunleye (November 29, 2012). "Mosun Filani, Tracy in ‘Jenifa’, gives birth". http://www.premiumtimesng.com/arts-entertainment/109205-mosun-filani-tracy-in-jenifa-gives-birth.html. 
  9. "Mosun Filani Set To Come Back To The Movie Industy After A Long Break…". Aprokcity. Archived from the original on February 13, 2016. Retrieved February 5, 2016.