Jump to content

Marie Curie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Maria Sklodowska-Curie)
Marie Skłodowska–Curie
Ìbí(1867-11-07)7 Oṣù Kọkànlá 1867
Warsaw, Vistula Land, Russian Empire
Aláìsí4 July 1934(1934-07-04) (ọmọ ọdún 66)
Passy, France
Ará ìlẹ̀Rosia, niwaju Fransi
Ọmọ orílẹ̀-èdèPolandi
Pápáphysics, chemistry
Ilé-ẹ̀kọ́University of Paris
Ibi ẹ̀kọ́University of Paris
ESPCI
Doctoral advisorHenri Becquerel
Doctoral studentsAndré-Louis Debierne
Óscar Moreno
Marguerite Catherine Perey
Ó gbajúmọ̀ fúnradioactivity, polonium, radium
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1903)
Davy Medal (1903)
Matteucci Medal (1904)
Nobel Prize in Chemistry (1911)
Religious stanceAgnostic
Notes
She is the only person to win Nobel Prizes in two sciences.
She was the wife of Pierre Curie, and the mother of Irene Joliot-Curie and Ève Curie.

Marie Salomea Skłodowska-Curie (Ojo keje, osu kankanla, odun 1867 – Ojo Kerin, osu keje, odun 1934) je onimo fisiyiki ati onimo kemistri omo orile-ede Poland to di ara Fransi lojowaju. O je asiwaju ninu papa radiolilagbara ati eni akoko to gba Ebun Nobel meji[1] — ninu fisiyiki ati kemistri. Ohun na lo tun je obinrin akoko to je ojogbon ni Yunifasiti ilu Paris.


  1. "Nobel Laureate Facts". Retrieved 26 November 2008.