Nkan oṣù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Figure showing the progression of the menstrual cycle and the different hormones contributing to it

Nkan oṣù, tí a tún mọ̀ sí àlejò obìnrin[1] jẹ́ ṣíṣàn jáde papọ̀ ẹ̀jẹ̀ àti ikun tí a ń dà pè ní nkan oṣù ni ónma ń jáde láti inú àpò-lùkẹ́ tabí ilé-ọmọ obìnrin gba inú òbò jáde.[2] Nkan oṣù àkọ́kọ́ sábà ma ń bẹ̀rẹ̀ lára ọmọdé tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ sé ipò wúndíá tàbí "ọmọge" ní dédé ọmọ ọdún méjìlá sí ọdún mẹ́ẹ̀dógún, àsìkò yí a ń pè ní àsìkò ìbàlágà.[1]Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ṣeé ṣe kí nkan oṣù yí ó tètè bẹ̀rẹ̀ ní nkan bí ọmọ ọdún mẹ́jọ nígbà míràn tí kò sì burú rárá. [2]Àmọ́ ní àwọn ìlú tí ìdàgbà-sókè wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ ń gbèrú, iye ọjọ́-ori tí ọmọbìnrin lè kọ́kọ́ rí nkan oṣù rẹ̀ máa ń bérẹ̀ láti ọdún mẹ́rìndíndlógún sí mẹ́ẹ̀dógún, àmọ́ ní àwọn ìlú tí wọ́n ti gòkè àgbà, ó lè tètè bérẹ̀. [3] The typical length of time between the first day of one period and the first day of the next is 21 to 45 days in young women, and 21 to 31 days in adults (an average of 28 days).[2][3]

Ṣiṣẹ́ nkan oṣù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bí nkan oṣù bá ti bẹ̀rẹ̀, ó ma ń sábà lò tó ọjọ́ méjì sí ọjọ́ méje gbako kí ó tó dá. [2] Nígbà tí nkan oṣù kìí wá lára obìnrin mọ́ nígbà tí wọ́n bá ti pé ọmọ ọdún márùndíláàdọ́ta sí àádọ́ta ọdún, àsìkò yí ni wọ́n ń pè ní mènópọ́ọ̀sì.[4] Periods also stop during pregnancy and typically do not resume during the initial months of breastfeeding.[2]

Àwọn alamí nkan oṣù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Yóò tó ìdá ọgọ́jọ àwọn obìnrin ni wọ́n ma ń ní alamí kan tí yóòa tọ́ka sí bí ara wọn ṣe ń palẹ̀mọ́ fún nkan oṣù tí ó ń bọ̀.[5] Àwọn àẹẹrẹ tí ó sábà ma ń fara hàn ni: inú kíkún, rírẹ̀wẹ̀sì, pínpúùsì, fífẹ́lẹ́ ọmú àti yíyí padà ìṣesí.[6]Gbogbo àwọn alamí tí a kà sílẹ̀ yí ni ó ṣe é ṣe kí kó ipa kan tàbí òmíràn lára awọn obìnrin ìdá ogú sí ọgbọ̀n, èyí túmọ̀ sí wípé nkan oṣù yóò dé láìpẹ́. [5] In 3 to 8%, symptoms are severe.[5]

Ipò ìlera ẹni tí ó ń ṣe nkan alejò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bí nkan àlejò obìnrin kò bá ì tíì bẹ̀rẹ̀, pàá pàá jùlọ lára àwọn ọ̀dọ́mọdé-bìnrin tí ọjọ́-ori wọn kò tíì ju ọdún mẹ́ẹ̀dógún lọ, tàbí nkan àlrjò kò wá fún bí àádọ́sàán ọjọ́ (90 days), àsìkò yí ni awọn gẹ̀ẹ́sì ń pè ní amenorrhea.[2]Lára àwọn ìṣòro tí ó lè rọ̀ mọ́ nkan àlejò obìnrin ni inú rírun apọ̀jù ẹ̀jẹ̀.[2] Menstruation in other animals occur in primates (apes and monkeys).[7][8]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Women's Gynecologic Health. Jones & Bartlett Publishers. 2011. p. 94. ISBN 9780763756376. https://books.google.com/books?id=pj_ourS3PBMC&pg=PA94. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 2.5 2.6 {{cite web|title=Menstruation and the menstrual cycle fact sheet|url=http://www.womenshealth.gov/publications/our-publications/fact-sheet/menstruation.html%7Cwebsite=Office of Women's Health|access-date=25 June 2015|date=23 December 2014|url-status=dead|archive-url=https://web.archive.org/web/20150626134338/http://www.womenshealth.gov/publications/our-publications/fact-sheet/menstruation.html%7Carchive-date=26 June 2015|df=dmy-all}}
  3. 3.0 3.1 "Menstruation in girls and adolescents: using the menstrual cycle as a vital sign". Pediatrics 118 (5): 2245–50. November 2006. doi:10.1542/peds.2006-2481. PMID 17079600. 
  4. "Menopause: Overview". nichd.nih.gov. 28 June 2013. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 8 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. 5.0 5.1 5.2 "Premenstrual syndrome and premenstrual dysphoric disorder". American Family Physician 84 (8): 918–24. October 2011. PMID 22010771. 
  6. "Premenstrual syndrome (PMS) fact sheet". Office on Women's Health. 23 December 2014. Archived from the original on 28 June 2015. Retrieved 23 June 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Kristin H. Lopez (2013). Human Reproductive Biology. Academic Press. p. 53. ISBN 9780123821850. https://books.google.com/books?id=M4kEdSnS-pkC&pg=PA53. 
  8. "The evolution of human reproduction: a primatological perspective". American Journal of Physical Anthropology Suppl 45: 59–84. 2007. doi:10.1002/ajpa.20734. PMID 18046752.