Nkwobi
Ìrísí
Spicy cow feet jẹ́ oúnjẹ aládùn tó wọ́pọ́ ní àwọn ilé ounjẹ , tí a tún mọ̀ sí nkwobi. Irú Oúnjẹ yìí wọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹ̀yà Igbo.[1][2] Ó jẹ́ ọbẹ̀ tí a fi òpó ẹ̀sẹ̀ ẹran màlúù sè.[3]
Àwọn èròjà tí a fi n pèsè rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn èròjà tí a ní lò láti fi se ohun ìpanu àwọn ni epo pupa, kaun, èròjà nọ́tmẹẹ̀gì, ewé utazi, ata, alùbọ́sà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ọ̀nà míràn tí a lè potash ni ngu, a lè lo ewé lespinach dípò utazia tí kò bá sí ní tòsí .[4][5][6][7] A sábà máa ń se Nkwobi ní ilé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó wọ́pọ̀ ní Ilé àwọn oloúnjẹ. Ọbẹ̀ náà wáyé látara ẹsẹ ẹran màlúù tí a ti bọ̀ pẹ̀lú alùbọ́sà àti àwọn oríṣiríṣi èròjà [8][9] Edé Calabash nutmeg àti ata lílọ̀ ní a ma fi kun lẹ́yìn ẹ̀ [10] Ẹ̀sẹ̀ màlúù tí a ti bọ̀ náà ní a ó pòpọ̀ mọ́ òróró, sì rọra ròó kó má báà jóná [11][12]
Ẹ tún wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Cow's trotters
- List of beef dishes
- List of African dishes
- Tripe
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Staff, Chef's Pencil. "Nkwobi/Spicy Cow Foot Delicacy Recipe". Chef's Pencil (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-06-05. Retrieved 2022-06-05.
- ↑ "Nkwobi: Easy Ibo Spicy Cow Foot Delicacy to Die For". 9jafoods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-12. Retrieved 2022-06-06.
- ↑ "Nkwobi: A mouth-watering delicacy from the East!". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-21. Retrieved 2022-06-11.
- ↑ says, Fermenting Ugba/Ukpaka-My Diaspora Kitchen (2017-11-17). "Nkwobi: The Nigerian Spicy Cow foot Special.". My Diaspora Kitchen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-05.
- ↑ Dobby (2014-08-09). "How to make Nkwobi". Dobby's Signature (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-06.
- ↑ "Nkwobi - Spicy Cow Foot Recipe". Sisi Jemimah (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-10-14. Retrieved 2022-06-06.
- ↑ Lete, Nky Lily (2013-02-25). "How to Make Nkwobi : Nigerian Spicy Cow Foot". Nigerian Food TV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-06.
- ↑ "Nkwobi recipe". The Pretend Chef (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-11-29. Retrieved 2022-06-06.
- ↑ Travel, Ou; Tour (2020-12-30). "How to make Nkwobi". Ou Travel and Tour (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-11.
- ↑ "Nkwobi: Spicy Cow Foot". All Nigerian Recipes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-05.
- ↑ "Nkwobi | How To Make Nigerian Desserts". All Nigerian Foods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-05.
- ↑ RITA (2020-09-19). "Food tips: How to make your Nkwobi spicy, yummy!". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-11.