Odó
Ìrísí
Odó ni ohun-èlò ilé ìdáná kan tí a má ń sábàá lò láti fi lọ ata, gún ẹ̀wà, èlùbọ́ Iyán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ nípa fífi ọmọ odó gún wọn pọ̀ títí yóò fi rí bí a tí ń fẹ́.
Ìrísí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Odó ( /ˈmɔrtər/) tí a ń wí yí ni ìrísí rẹ̀ dà bí igbá roboto.
Ohun tí wọ́n fi ń ṣe odó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n ma ń ṣe odó láti ara akọ igi, irin,sẹ̀rámíìkì, tàbí akọ òkúta bí àpáta