Jump to content

Ojo Olayiwola Oyebode

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ojo Olayiwola Oyebode
10th Deputy Speaker of the Kwara State House of Assembly
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
18 March 2023
AsíwájúAdetiba-Olanrewaju Raphael Olalekan
Member of the Kwara State House of Assembly
from Oyun Local Government
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
18 March 2023
ConstituencyOke-ogun
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kẹrin 1975 (1975-04-04) (ọmọ ọdún 49)
Ipee,Oyun Local Government Kwara State Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress
Alma mater
Occupation
  • Politician
  • Legal Practitioner

Ojo Olayiwola Oyebode to je oloselu ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà to n sójú àgbègbè Odo-Ogun, ìjọba ìbílẹ̀ Oyun ni ile ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlè Kwara ni igbákejì olórí ile kewa ti ile ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlè Kwara . [1] [2]

Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ojo a bi Ojo 4 osu kẹrin ọdún 1975 ni ilu Ipee, ni ìjọba ìbílè Oyun ni ipinle Kwara . Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Baptist LGEA Ìpee, láàárín ọdún 1984 sí 1989 àti Jama’at Nasir Islam School Owu-Isin Secondary School, ní ìpínlẹ̀ Kwara láàárín ọdún 1996 – 2002. Ojo kọ ẹkọ iṣiro ni ilé ẹ̀kọ́ Federal Polytechnic Offa, si gba Iwe-ẹkọ giga ti Orilẹ-ede ni ọdun 2005.

Laarin odun 2007-2010, Ojo lo je ọmọ ile ìgbìmò Ipee Ward nijoba ìbílè Oyun nipinle Kwara ko too di igbákejì alága ijoba ibile Oyun. Lodun 2019, Ojo dije labe egbe oselu All Progressive Congress gege bi ola to n soju ẹkún Oke-ogun nile ìgbìmọ̀ asofin ipinle Kwara ti o si jawe olubori tun ibo lodun 2023 lorileede Naijiria, won si yan an lati se igbá-kejì olori ile igbimo asofin Hon. . Salihu Yakubu-Danladi ni Apejọ kẹwa. [3]