Olómìnira ilẹ̀ Kóngò (Léopoldville)
Appearance
|
Orile-ede Olominira ile Kongo (Faransé: République du Congo) je aladawa olominira to je didasile leyin igba ti imusin Kongo Belgiomu gba ominira ni 1960. Oruko yi lo je titi di 1 August 1964,[1] nigba ti won yi si Olominira Toselu ile Kongo, lati yatosoto si orile-ede keji toni bode mo to n je Olominira ile Kongo, imusin Kongo Fransi tele.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |