Jump to content

Oníṣe:Demmy/Sandbox/anotherlayout

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹkúàbọ̀Wikipedia,
ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́ẹnikẹ́ni le túnṣe.
01:56 (UTC); Ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọjọ́ 16 Oṣù Bélú ọdún 2024
Àyọka 34,625 wà ní èdè Yorùbá.
Àwọn èbúté · Àwọn ẹ̀ka · Ìrànlọ́wọ́

Ìlànà · Àwọn Ìbéèrè Wíwọ́pọ̀ · Àgbàjọ · Àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ Wikipedia · Ọrẹ · WAP · Acessibilidade · Contato

   Àyọkà ọ̀sẹ̀ yìí
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀. Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè ÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)


   Ìsẹ̀lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ bíi òní ní... ọjọ́ 16 Oṣù Bélú
Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 16 Oṣù Bélú
   Ṣé ẹ mọ̀ pé...

Great Mosque of Algiers


   Àwòrán ọjọ́ òní

Buddha Daibutsu, ni Kamakura, Japan.


 
Ìròyìn


Àwọn ẹ̀ka àyọkà
Àṣà

Lítíréṣọ̀Eré-ìdárayáFílmùOrinTíátàÌṣeròyìnTẹlifísànRédíò

Tẹknọ́lọ́jì

Iṣẹ́ẹ̀rọInternetÀfigbébánisọ̀rọ̀Kọ̀mpútà

Àwùjọ

ẸbíFàájìÒfinỌ̀rọ̀-òkòwòÌnáwóÌṣèlúỌ̀rọ̀-àwùjọÈnìyànẸ̀kọ́Ìmòye

Sáyẹ́nsì

Ìtòràwọ̀ÒfurufúỌ̀gbìnSáyẹ́nsì kọ̀mpútàFísíksìÌwòsànÀdánidáKẹ́místrìBàíọ́lọ́jì

Mathimátíkì

Áljẹ́bràÌtúwòÌṣíròÌṣedọ́gbaJẹ́ọ́mẹ́trìNọ́mbàTẹ̀ọ́rẹ́mùỌgbọ́n

Jẹ́ọ́gráfì

AyéAdágúnOrílẹ̀-èdèÒkunOrílẹ̀ÌlúÁfríkàÁsíàEuropeGúúsù Amẹ́ríkàÀríwá Amẹ́ríkà

Ìtàn

OgunOrílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀Ilẹ̀ọbalúayéỌ̀rọ̀-ayéijọ́un

Ìgbésíayé

Olórí orílẹ̀-èdèOníṣọ̀nàÒṣeréOnímọ̀sáyẹ́nsìAmòyeOlóṣèlúOlùkọ̀wéOníṣòwò

Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́

Ẹ̀sìn YorùbáÌmàleẸ̀sìn KrístìÌṣebúddhàÌṣehíndù

Ìlera

ÌmáralókunÌdárayáAmáralókunìtọ́jú ìleraÀrùnỌ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn

Kömək səhifələri
Àdàkọ:Şablon:VikipediyaKomekSaheleri
   Wikipedia
Wikipedia

Ìrànlọ́wọ́ · Άρθρα προς επιμέλεια · Άρθρα προς μετάφραση · Àwọn ẹ̀tọ́àwòkọ · Άρθρα προς επέκταση

Àgbàjọ
Abẹ́ igi · Συχνές ερωτήσεις (FAQ) · Πολιτική · Πολιτική διαγραφής · Αμμοδόχος · Προτεινόμενα θέματα για νέα άρθρα · Άρθρα ζωτικής σημασίας · Νέα άρθρα · Διαχειριστές
Ìlànà fún àwọn oníṣe tuntun
Οδηγός για νέους χρήστες · Τι είναι η Βικιπαίδεια · Τι δεν είναι η Βικιπαίδεια · Απλοί κανόνες · Ουδετερότητα · Εικόνες · Πώς να επεξεργαστείτε μια σελίδα · Οδηγός μεταφράσεων · Επιφόρτωση αρχείου


Àwọn ìṣẹ́-ọwọ́ míràn
Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo ise-owo miran :
Wiktionary
Wiktionary
Awon itumo oro ati thesaurus
Wikinews
Wikinews
Fun iroyin ofe(Gẹ̀ẹ́sì)
Wikiquote
Wikiquote
Collection of quotations
Wikibooks
Wikibooks
Free textbooks and manuals
Wikispecies
Wikispecies
Directory of species
Wikisource
Wikisource
Free-content library
Wikiversity
Wikiversity
Free learning materials and activities
Commons
Common
Shared media repository
Meta-Wiki
Meta-Wiki
Wikimedia project coordination