Orúkọ Yorùbá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Oruko Yoruba naa ni iwe yii da le. O soro nipa jije oruko, eto ikomojade, oruko amutorunwa, oruko abiso ati oruko mti won n fun abiku, iyato laarin oruko ati alaje ki o to wa fi orile pari re. Ibeere wa ni opin iwe fun idanrawo. Awon itumo awon oro ti ta koko naa si wa pelu.Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • C.L. Adeoye (1982), Oruko Yoruba. Ibadan, Nigeria: University Press ltd. Oju-iwe = 129'